From Wikipedia, the free encyclopedia
Ngozi Okonjo-Iweala tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹfà ọdún 1954 jẹ́ onímọ̀ ètò ìṣúná, ó sì tún jẹ́ Alákòóso fún ètò ìnáwó àti Alákòóso fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèrè tẹ́lẹ̀ fún orílẹ̀-èdè Njíríà [1]. Ó Jẹ́ ìkan láàárín àwon adarí ni Standard Chartered Bank, Twitter, Global Alliance for Vaccines and Immunizations àti African Risk Capacity (ARC).[2]Okonjo - Iweala tí si ṣé gẹ́gẹ́ bí ojisẹ nípa ọ̀rọ̀ owó ni ẹ méjì ni abẹ àkóso àwọn Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀, Olusegun Obasanjo àti Goodluck Jonathan.[3]
Ngozi Okonjo-Iweala | |
---|---|
Minister of Finance | |
In office 17 August 2011 – 29 May 2015 | |
Ààrẹ | Goodluck Jonathan |
Asíwájú | Olusegun Olutoyin Aganga |
Arọ́pò | Kemi Adeosun |
In office 15 July 2003 – 21 June 2006 | |
Ààrẹ | Olusegun Obasanjo |
Asíwájú | Adamu Ciroma |
Arọ́pò | Nenadi Usman |
Coordinating Minister for the Economy | |
In office 17 August 2011 – 29 May 2015 | |
Ààrẹ | Goodluck Jonathan |
Asíwájú | Olusegun Olutoyin Aganga |
Arọ́pò | Position abolished |
Minister of Foreign Affairs | |
In office 21 June 2006 – 30 August 2006 | |
Ààrẹ | Olusegun Obasanjo |
Asíwájú | Oluyemi Adeniji |
Arọ́pò | Joy Ogwu |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Kẹfà 1954 Ogwashi Ukwu, Nigeria |
Education | Harvard University (BA) Massachusetts Institute of Technology (MA, PhD) |
Wọ́n bíi sì Ogwashi-Ukwu ni ìpínlè Delta ni Nàìjíríà. Bàbá rẹ̀ ni Professor Chukwuka Okonjo tí ó jẹ́ ọba láti ìdílé Obahai ni Ogwashi-Ukwu.[4] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Queen's School ni Enugu, St. Anne's School ni Ìbàdàn àti International School ni Ibadan. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Harvard University ni USA ni ọdún 1978, ó sì gboyè nínú Economics ni ọdún 1976.[5] Ní ọdún 1981, ó gbà PhD nínú regional economics and development láti Massa Institute of Technology (MIT).[6] Ó gbà iranlọwọ láti ọ̀dọ̀ American Association of University Women tí ó fi tẹ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ.[7] Ó fé Dr. Ike bá Iweala, wọn si bíi ọmọ mẹrin.[8][9][10]
Okonjo Iweala tí si ṣé fun ilé ifowopamo tí agbaye fún ọdún meedọgbọn, ó sì gbà ipò kejì gẹ́gẹ́ bí adarí.[11] Ní ọdún 2010, ó di alaga fún Idà replenishment, èyí tí wọn fi fún $49.3 billion fún àwọn orílẹ̀ èdè tó tálákà jùlọ.[12][13] Ní ìgbà tí ó wà ní ilé ifowopamo àgbáyé, ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Effective Development Cooperation with Africa. Okonjo ṣe minisita fún ọ̀rọ̀ owo ni Nàìjíríà ni ẹ méjì, ó sì tún ṣe minisita fún ètò ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèèrè.[14] Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má kókó dé ipò náà. Óun lọ síwájú ìjíròrò pẹlu Paris Club, èyí tí ó fi jẹ ki wọn fagilé gbèsè $30billion tí Nàìjíríà jẹ.[15] Ní ọdún 2003, ó gbìyànjú láti jẹ ki idagbasoke wá nínú owó ti Nàìjíríà gbà nípa títa èpò ròbì, ó ṣe òfin pé tí wọn ba tá iye owó kàn, pé kí wọn fi sì ilẹ̀ ifowapamo.[16] Ó tun ṣe ìfihàn àwọn owó tí ipinle kàn kán gba sínú ìwé ìròyìn.[17] [18] Pẹlu àtìlẹyìn láti ọwọ́ ilé ifowopamo agbaye àti IMF tí ìjọba Nàìjíríà, ó dẹkùn jìbìtì tí àwọn kàn ṣe nípa gbígbà owó fún àwọn òṣìṣẹ́ tí kò sì.[19] Ó di adarí fún ile ifowopamo agbaye ni osù Kejìlá ọdún 2007.[20][21] Ní ọdún 2011, wọn tún fi jẹ minista fún ọ̀rọ̀ owó ni ìgbà kejì.[22] Ó pèsè ìṣe fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn nípa ètò Youth Enterprise with Innovation (YouWIN),[23] ó sì rán àwọn obìnrin àti ọ̀dọ́ nípa ètò Growing Girls and Women in Nigeria (GWIN).[24][25] Ó ri ọ̀pọ̀lọpọ̀ wàhálà nígbà tí wón fi owó lè epo ni 2012.[26][27] Okonjo je ìkan lára àwọn alaga fún Global Commission for the Economy and Climate[28] àti Partnership for Effective Development Cooperation.[29] Ní ọdún 2015 - 2016, ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ International commission on Financing Global Education Opportunities. Okonjo - Iweala ni oludasile NOI-Polls[30] àti Centre for the study of Economics of Africa (C-SEA).[31] Ní ọdún 2012, ó du ipò olùdarí fún ilé iṣẹ́ ifowopamo tí agbaye.[32][33] Ní ọdún 2019, ó dára pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ UNESCO's International Commission on the Future of Education.[34] Ní ọdún 2020, olùdarí IMF, Kristalina Georgieva fi Okonjo ṣe ikan lára àwọn ònímoran fún àwọn ìdojúkọ nínú ètò ìmúlò wọn.[35] African Union náà fi ṣe aṣojú pàtàkì fún wọn láti lè dẹ́kun ipa tí àrùn Corona Virus ni lórí ọ̀rọ̀ aje tí àgbègbè náà.[36]
Ọdún | Ẹgbẹ́ | Ipò | Ref |
---|---|---|---|
2017 | Japan International Cooperation Agency | Ọmọ ẹgbẹ́ | [37] |
2016 | Asian Infrastructure Investment Bank | Ọmọ ẹgbẹ́ | [38] |
2016 | GAVI | Alága | |
(2003-2006, 2011-2015) | African Development Bank | Ìkan laarin awọn adarí | [39] |
2018 | Ìkan laarin awọn adarí | [40] [41] | |
2017 | Standard Chartered PLC | Ìkan laarin awọn adarí | [42] |
2015 | Lazard | Onímòràn pàtàkì | [43] |
2019 | Carnegie Endowment for International Peace | Ọmọ ẹgbẹ́ | [44] |
2018 | Bloomberg New Economy Forum | Ọmọ ẹgbẹ́ | [45] |
2014 | Results for Development (R4D) | Ọmọ ẹgbẹ́ | [46][47] |
2014 | Women's World Banking | Ọmọ ẹgbẹ́ | [48] |
2013 | The B Team | Ọmọ ẹgbẹ́ | [49][50] |
2007 | Friends of the Global Fund Africa | Ọmọ ẹgbẹ́ | [51] |
2007 | Global Financial Integrity (GFI) | Ọmọ ẹgbẹ́ | [52] |
2017 | African Risk Capacity | Alága | [53] |
African University of Science and Technology | Alága | ||
Georgetown Institute for Women | Ọmọ ẹgbẹ́ | [54] | |
Global Business Coalition for Education | Ọmọ ẹgbẹ́ | [55] | |
Mandela Institute for Development Studies (MINDS) | Ọmọ ẹgbẹ́ | [56] | |
Mercy Corps | Ọmọ ẹgbẹ́ | [57] | |
Nelson Mandela Institution | Alága | [58] | |
2013 | One Campaign | Ọmọ ẹgbẹ́ | [59] |
Oxford Martin School | Ọmọ ẹgbẹ́ | [60] | |
Vital Voices | Ọmọ ẹgbẹ́ | [61] | |
Okonjo-Iweala gba òye ẹ̀yẹ láti ọwọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga merin lélógún tí University of Pennsylvania (2013),[62] Yale University (2015),[63] Amherst College (2009)[64] Trinity College, Dublin (2007)[65] Brown University (2006),[66] Colby College (2007).,[67] Northern Caribbean University, Jamaica, Abia State University, Delta State University, Abraka, Oduduwa University, Babcock University, Universities of Port Harcourt, Calabar, ati Ife (Obafemi Awolowo) ati Tel Aviv University.[68]
Ọdún | Ẹ̀bùn | Ref |
---|---|---|
2017 | Howard University - Vanguard Award | |
2014 | Fortune top 50 Greatest World Leaders | [69] |
2017 | Madeleine K. Albright Global Development Award, Aspen Institute | |
2015 | Power with Purpose Award, Devex Development Communications Network | |
2016 | Global Fairness Award, Global Fairness Initiative | |
2011 | President of the Italian Republic Gold Medal, Pia Manzu Centre | |
2011 | Global Leadership Award, Chicago Council on Global Affairs | |
2010 | Global Leadership Award, Columbia University School of International and Public Affairs | |
2010 | Bishop John T. Walker Distinguished Humanitarian Service Award | |
2004 | TIME’s European Heroes Award | |
2004 | Finance Minister of the Year, Africa Investor Magazine | |
2004 | Finance Minister of the Year for Africa and the Middle East, The Banker | |
2005 | Global Finance Minister of the Year, Euromoney | |
2005 | Finance Minister of the Year for Africa and the Middle East, Emerging Markets Magazine | |
2014 | Top 100 Most Influential People in the World (Time) | |
2011 & 2012 | The Top 100 Global Thinkers(Foreign Policy) | [70] |
2011, 2012, 2013 and 2014 | The Top 100 Most Powerful Women in the World (Forbes) | |
2012 | The Top 3 Most Powerful Women in Africa (Forbes) | |
2011 | the Top 10 Most Influential Women in Africa (Forbes) | |
2011 | The Top 100 Women in the World (The Guardian) | |
2011 | The Top 150 Women in the World (Newsweek) | |
2011 | The Top 100 most inspiring people in the World Delivering for Girls and Women (Women Deliver) | |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.