From Wikipedia, the free encyclopedia
Naomi Osaka (大坂なおみ Ōsaka Naomi , born 16 October 1997) jẹ́ agbá bọ́ọ̀ ẹlẹ́yin orí ọ̀dàn fún ilẹ̀ Olómìnira Japan. Òun ni agbá bọ́ọ̀lù ẹlẹ́yin orí ọ̀dàn ará Japan àkọ́kọ́ tó gba Ife-ẹ̀yẹ ìdíje Grand Slam, nígbà tí ó borí alátakò rẹ̀ Serena Williams nínú àṣekágbá ìdíje Open Amerika 2018 ti ọdún 2018.[2] Osaka ti dé ipò 1k láglagbaye tó sì jẹ́ ipò rẹ̀ tó ga jọ ní ọjọ́ Kejìdínlọ́gbọn oṣù Kínní ọdún 2019 ( 28, 2019).[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Osaka at 2017 Wimbledon Championships | |
Orílẹ̀-èdè | Japan |
---|---|
Ibùgbé | Boca Raton, Florida, United States |
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kẹ̀wá 1997 Chūō-ku, Osaka, Japan |
Ìga | 1.80 m (5 ft 11 in) |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | September 2013 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (two-handed backhand) |
Olùkọ́ni | Jermaine Jenkins |
Ẹ̀bùn owó | $10,733,311 |
Ojúewé Íntánẹ́ẹ̀tì | naomiosaka.com |
Iye ìdíje | 178–119 (59.93%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 5 WTA, 0 ITF[1] |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 1 (January 28, 2019) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 2 (March 8, 2021) |
Open Austrálíà | W (2019, 2021) |
Open Fránsì | 3R (2016, 2018) |
Wimbledon | 3R (2017, 2018) |
Open Amẹ́ríkà | W (2018, 2020) |
Ìdíje WTA | RR (2018) |
Iye ìdíje | 2–14 (12.5%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 0 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 324 (April 3, 2017) |
Open Austrálíà | 1R (2017) |
Open Fránsì | 2R (2016) |
Wimbledon | 1R (2017) |
Open Amẹ́ríkà | 1R (2016) |
Fed Cup | WG II PO (2018) |
Hopman Cup | RR (2018) |
Last updated on: November 3, 2018. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.