Nana Kanga From Wikipedia, the free encyclopedia
Nana Hill Kagga Macpherson ti atun mo si 'Nana Kagga-Hill tabi 'Nana Hill' je omo orile ede Ùgándà, oje osere, ako ere, onimo ero ati agboroso iwuri.[1] O je gbajumo fun ise e ninu The Life, Beneath The Lies - The Series gegbi ako ere ati agbe ere jade pataki ati gege bi osere ninu Star Trek.,[2][3]
Nana Kagga Macpherson | |
---|---|
RealTVfilms se iforo wani lenuwo fun Nana Hill Kagga ni odun 2008. | |
Ọjọ́ìbí | Nana Kagale Kagga 6 Oṣù Kẹrin 1979 Uganda |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Ugandan |
Iléẹ̀kọ́ gíga |
|
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2003–titi di asiko yi |
Àwọn ọmọ | 3 |
Àwọn olùbátan | awon omo iya marun |
Oje okan ninu awon adajo Miss Uganda ni odun 2018.[4]
A bi Kagga si ilu Nairobi, Kenya fun awon obi ti o wa lati Uganda, kan ninu awon obi re je onimo ero. Kagga je Muganda, otun je omoba birin ni awon eya Baganda. Kagga je omo eleketa ninu omo mefa ti awon obi e bi. Ni asiko ti won bi, awon obi e wa lehin odi, ni asiko Oludari Idi Amin Kagga dagba si ebi olola. Yato fun baba ati baba-baba e, awon omo iya e merin na je onimo ero. Ilu Kampala ni Kagga n gbe pelu awon e meta. O gbo ede geesi ati ede Luganda.
Kagga pari ile eko alakobere ni Kampala Parents School. O darapo mo Gayaza High School, ile eko awon omo obinrin fun O-levels. O se A-levels ni Red Maids School, Bristol, ile eko awon omo ibinrin ti o ti dagba ju ni UK. Kagga loai il eko giga University of Birmingham, Birmingham, UK, ni ibi yi ni oti ko eko imo ero nipase titi epo robi. ni asiko isimi o ma n lo si Uganda lati se adari eto Jam Agenda lori WBS.[5]
Lehin ti o pari ile eko giga, Kagga ko lo ilu Florida ni ile USA, lehin igbana otun losi New Mexico ni Ilu Amẹ́ríkà. O sise ni ile ise Laguna gegebi oni mo ero ni Laguna nigba ti won sise pelu awon ologun.[6]
Kagga gbero lati se ise osere ni ilu Los Angeles osi ni awon aseyori kankan. Kagga kopa ninu awon ere Cowboys and Indians, A Good Day to Be Black and Sexy (Segment ‘Reprise’), He's Just Not That into You, Star Trek, CSI: NY – Boo, Life, Runway Stars. Ninu ere itage titi Amerika, Kagga ko ipa Mercy ninu ere Butterflies of Uganda ti Darren Dahms se, won yan ere na fun ami eye NAACP. Kagga ti kopa ninu opolopo fidio orin lati owo awon olorin bi P!nk, Amy Winehouse, Sting, Lenny Kravitz.[7] Kagga ti ko ipa ninu ipolowo orisirisi fun awon ilese KFC, Coors Light, Pepsi, DSW, Microsoft, APPLE, Tylenol, DOVE.[8] Ni igba ti owa ni ilu Amerika, Kagga ni ile itaja fun awon nkan ti oti pe ti osi ni iyi ni Santa Monica ti o pe ni A Vintage Affair.
Kagga pada si ilu Uganda ni odun 2009, o da ile ise sile ti oje Savannah MOON Ltd. Savannah MOOD labe akoso, Savannah MOON Productions won se agbejade ere The Life[9] ti won se afi han e ninu M-NET, jara telifisonu Beneath The Lies - The Series,[10]lowolowo bayi won se afihan e lori Urban TV ati MTN Uganda, How We See It. Savannah MOON tun gbe ere kan ti won pe akole e ni The Last Breath pelu Kampala Film School. Savannah MOON sise orisirisi lowo, ikan ninu e ni Taking Time, jara telifisonu ti on bo lona. Kagga da egbe kan si le You Are Limitless (YAL) o da si le ki oba le je nkan ti oma mu ori awon omo Afrika wu, ki won ba le se gbogbo nkan ti won fe se laye. Kagga tun sise pelu ile epo robi nla kan ni ilu Uganda.
Odun | Fiimu | Ipa | Oludrai | Akiyesi |
---|---|---|---|---|
2009 | Star Trek | Egbe atuko egbe | J.J. Abrams | Paramount Pictures |
He's Just Not That into You | Alejo inawo | Ken Kwapis | Universal Pictures | |
2008 | A Good Day to Be Black and Sexy (Segment Reprise) | Candi | Dennis Dortch | Magnolia Pictures |
2007 | Collision | Fiimu adase | ||
Hitch-hike | Fiimu adase | |||
Cowboys and Indians | omo India | Fiimu kukuru | ||
Odun | Akori | Ipa | Oludari | Akiyesi |
---|---|---|---|---|
2014 | Beneath The Lies - The Series | Adajo agba | Joseph Katsha Kyasi | Jara telifisonu Savannah MOON Productions |
2008 | Runway Stars | Angeli | Jara aye lujara | |
Life (NBC TV series) | omo dudu awelewa | Jara telifisonu, NBC | ||
2007 | CSI: NY – Boo | Josephine Delacroix | Joe Dante | jara telifisonu, CBS |
2006 | BET Stars | BET | ||
Year | Film/TV Series | Role | Notes |
---|---|---|---|
Mela | oludari | jara ayelujara | |
2018 | Reflections[13] | Oludasile, oludari | jara telifisonu pelu Cleopatra Koheirwe, Gladys Oyenbot, ati Housen Mushema |
2016 | The Last Breath | alase o nse | fiimu kukuru |
2014 | Beneath The Lies - The Series[14] | alase o nse | Jara telifisonu |
How We See It | agbalejo, oludari | eto ejo titi Uganda | |
2012 | The Life | Oludari | fiimu |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.