Miss Grand International
From Wikipedia, the free encyclopedia
Miss Grand International jẹ idije ẹwa kariaye fun awọn obinrin alailẹgbẹ. Ti ipilẹṣẹ ni Tháílàndì ni ọdun 2013.[1][2]
Quick Facts Ifihan pupopupo, Agekuru ...
Miss Grand International Organisation | |
---|---|
มิสแกรนด์อินเตอร์เนชันแนล | |
Ifihan pupopupo | |
Agekuru | MGI |
Awọn ipilẹ | 23 Kọkànlá Oṣù 2013 |
Motto | (En) Stop the wars and violence |
Iṣakoso | |
Olori | Nawat Itsaragrisil |
Igbakeji piresidenti | Teresa Chaivisut |
Agbegbe | Ni kariaye |
Ile Olori Ise patapata | Bangkok, Tháílàndì |
Adirẹsi | 1213/414, Soi Lat Phrao 94 (Pancha Mit), Lat Phrao Road, Phapphla, Wang Thonglang, Bangkok, Tháílàndì |
Ọmọ ẹgbẹ | > Awọn orilẹ-ede 70 |
Miss Grand International | Valentina Figuera (2019) |
Agbari ti o ni ibatan | |
Nwe | Miss Grand International Co., Ltd. |
Sub-organisation | Miss Grand Thailand Co., Ltd. |
Media lori ayelujara | |
Oju opo wẹẹbu | MissGrandInternational.com |
Miss Grand International 2020 |
Close
Ni ọdun 2019, keje iru rẹ to waye nilu Caracas Fenesuela lọjọ 25, oṣu Kẹwa, Omidan Valentina Figuera, to jẹ́ aṣoju orilẹede Fenesuela lo jawe olubori nibi eto naa. Orilẹ-ede ọgọta lo kopa ninu idije naa.[3]