Mawlid
From Wikipedia, the free encyclopedia
Mawlid, Mawlid an-Nabi ash-Sharif tàbí Eid Milad un Nabi ( المولد النبوي ní èdè Arabic) jé ayẹyẹ ọjọ́ ìbí anọ́bì Muhammad, [2], wọ́n sì ma ń sábà ṣe ayẹyẹ yí ní inú Oṣù Rabi' al-awwal, tí ó jẹ́ oṣù kẹta ti ònkà oṣù ojú ọ̀run àwọ Mùsùlùmí.[3] Rabi' al-awwal kéjìlá[4] ni ọjọ́ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀jọ̀gbọ́ Sunni fi ọwọ́ sí, Rabi' al-awwal ketadinlogbon si ni ijo ti òpòlopò òjògbón Shia fi owó sí, bi o tilè jé wípé kì I se gbogbo òjògbón Shia ni o fowo si ijo yi. Awon kan tún Ma un pe ayeye yi ni Maouloud ni ìwo oòrùn Africa.[5][6]
Mawlid | |
---|---|
àwon Muslumi Sunni Malaysian ní ìwóde Mawlid kan ni Putrajaya, 2013. | |
Also called | Mawlid an-Nabawī (المولد النبوي), Eid-e-Milad un-Nabi, Havliye, Donba, Maouloud, Gani[1] |
Observed by | Adherents of mainstream Sunni Islam, Shia Islam, Ibadi Islam and various other Islamic denominations. As a public holiday in Afghanistan, Algeria, Bahrain, Benin, Bangladesh, Brunei, Burkina Faso, Chad, Ethiopia, Egypt, Fiji, Gambia, Indian Subcontinent, Indonesia, Iran, Iraq, Jordan, Kuwait, Lebanon, Libya, Malaysia, Maldives, Mali, Mauritania, Morocco, Niger, Nigeria, Oman, Senegal, Somalia, Sudan, Tunisia, and Yemen |
Type | Islamic |
Significance | Traditional commemoration of the birth of Muhammad |
Observances | Hamd, Tasbih, public processions, Na`at (religious poetry), family and other social gatherings, decoration of streets and homes |
Ìtàn nípa ayẹyẹ na ti wà láti ayé àtijó nígbà tí orin àti ewì tí àwọn Tabi‘un ko láti yín Muhammadu di ohun tí wọ́n ń kó sì àwọn ènìyàn .[7] O wà nínú ìtàn pé olùdarí Mùsùlùmí àkókò tí ó kókó se ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Muhammadu ni Muzaffar al-Din Gökböri (d. 630/1233).[8] Àwọn Ottomans kéde rẹ̀ ni ọjọ́ ìsinmi ni odun 1588. [9] tí a mọ̀ sí Mevlid Kandil.[10]
Mawlid jẹ́ ọ̀rọ̀ tí wọ́n ún lọ ní àwọn ibi kan ni àgbáyé, bí àpẹẹrẹ, Orílẹ̀ èdè Egypti gẹ́gẹ́ bí orúkọ fún òjọ́ ìbí àwọn ènìyàn pàtàkì nínú ìtàn bi Sufi saints.[11]
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹgbẹ́ Mùsùlùmí ni wón fi owó sì ṣíṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Muhammadu.[12][13] ṣùgbọ́n, láti ìgbà tí Wahhabism-Salafism, Deobandism, Ahl-i Hadith àti Ahmadiyya to dẹ́,[14] ọ̀pọ̀lọpọ̀ Mùsùlùmí bẹ̀rẹ̀ si ún lòdì sí ṣíṣe ayẹyẹ náà, wón ní kí ún se ayẹyẹ tó tọ́(bid'ah or bidat).[15][16] Wọ́n kaMawlid sí òjọ́ ìsinmi ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ Orílẹ̀ èdè tí Mùsùlùmí ti pò ju ẹ̀sìn mìíràn lo, yàtò sí orílè-èdè bi Saudi Arabia àti Qatar. Àwọn orílè-èdè míràn tí kì ún se mùsùlùmí ni ó poju níbè ṣùgbọ́n tí Mùsùlùmí pò níbè, orílè-èdè bí India, Tanzania àti Ethiopia, àti beebe lọ, tún ka ọjọ́ ìṣe ayẹyẹ Mawlid gẹ́gẹ́ bi ọjọ́ ìsinmi.[17]