![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/1/1c/Mary_Slessor.jpg/640px-Mary_Slessor.jpg&w=640&q=50)
Mary Slessor
From Wikipedia, the free encyclopedia
Mary Mitchell Slessor (Ọjọ́ kejì oṣù kejìlá ọdún 1848 si ọjọ́ kẹtàlá oṣù kínní ọdún 1915) jẹ ajihinrere si orílẹ̀-èdè Naijiria lati ilu Scotland. Ní kété tí o dé orílẹ̀-èdè Naijiria, Slessor bẹ̀rẹ̀ si kọ èdè Efik, ti o jẹ́ èdè ìbílẹ̀ níbẹ̀. Nítorí ìmò ti o ni nipa èdè ìbílẹ̀ yi ati ìsẹ̀dá rẹ gẹ́gẹ́ bi ẹni ti o nígbo'yà, Slessor rí ojú rere àwon ará ìlú náà o si rọrùn fun un lati tan ẹsin ọmọ lẹyin Kristi ka ti o si tun ni anfani lati ṣe agbatẹru ẹtọ àwon obìnrin àti àmójútó àwon ọmọde ni ilẹ̀ náà. Ohun ti o sọ ọ di gbajúgbajà ni bi o ṣe da aṣa pípa àwon ọmọ-ọwọ ti o jẹ ìbejì duro laarin àwon ẹ̀yà Ibibio, ni apa gúsù-ìlà-oòrùn orílẹ̀-èdè Naijiria.
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Aláìsí ...
Mary Slessor | |
---|---|
![]() Mary Slessor | |
Ọjọ́ìbí | 2 December 1848 (1848-12-02) Aberdeen, Scotland |
Aláìsí | 13 January 1915(1915-01-13) (ọmọ ọdún 66) Use Ikot Oku, Itu, Akwa Ibom State, Nigeria formally known as Calabar province. |
Orílẹ̀-èdè | Scottish |
Gbajúmọ̀ fún | Christian missionary work in Africa; promoting women's rights and rescuing children from infanticide. |
Close