From Wikipedia, the free encyclopedia
Martin Heidegger (26 September 1889 – 26 May 1976) (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈmaɐ̯tiːn ˈhaɪ̯dɛɡɐ]) je onimoye to ni ipa pataki ara ile Jemani. Iwe re to ko to se koko ni, Being and Time. Heidegger si n fa ariyanjiyan nitori ipa to ko ninu Nazism ati itileyin to ni fun Adolf Hitler.
Martin Heidegger | |
---|---|
Orúkọ | Martin Heidegger |
Ìbí | 26 September 1889 Meßkirch, Germany |
Aláìsí | 26 Oṣù Kàrún 1976 (ọmọ ọdún 86) Freiburg im Breisgau, Germany |
Ìgbà | 20th-century philosophy |
Agbègbè | Western Philosophy |
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ | Phenomenology · Hermeneutics · Existentialism |
Ìjẹlógún gangan | Ontology · Metaphysics · Art · Greek philosophy · Technology · Language · Poetry · Thinking |
Àròwá pàtàkì | Dasein · Gestell · Heideggerian terminology |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.