Mahershala Ali
From Wikipedia, the free encyclopedia
Mahershala Ali ( /məˈhɜrʃələ/; tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Mahershalalhashbaz Gilmore, tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kejì, ọdún 1974) jẹ́ òṣèrékùnrin láti orílẹ̀-èdè Amerika. Ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ bíi Academy Awards méjì, Golden Globe Award àti Primetime Emmy Award. Ìwé ìròyìn Times to orúkọ rẹ̀ pọ̀ mó àwọn ọgọ́rùn-ún ènìyàn tó lọ́á jù lọ ní àgbááyé, ní ọdún 2019,[2] àti 2020, The New York Times fi sípò karùn-úndínlọ́gbọ̀n lára àọn òṣèré tó lọ́lá jù lọ.[3]
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Orúkọ míràn ...
Mahershala Ali | |
---|---|
Ali at the 2019 San Diego Comic-Con | |
Ọjọ́ìbí | Mahershalalhashbaz Gilmore 16 Oṣù Kejì 1974 (1974-02-16) (ọmọ ọdún 50) Oakland, California, U.S.[1] |
Orúkọ míràn | Mahershala Karim-Ali, Hershal Gilmore |
Ẹ̀kọ́ | Saint Mary's College, California (BA) New York University (MFA) |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 2001–present |
Olólùfẹ́ | Amatus Sami-Karim (m. 2013) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Awards | Full list |
Close