Macy Gray
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America / From Wikipedia, the free encyclopedia
Macy Gray (oruko abiso Natalie McIntyre, 6 September 1967 ni Canton, Ohio, USA)[1][2] je akorin-adaorin R&B ati soul, atokun awo-orin, ati osere ara Amerika to gba Ebun Grammy, o gbajumo fun ohun hiha re ati iru ikorin to jo bi Billie Holiday ati Betty Davis.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Quick Facts Background information, Orúkọ àbísọ ...
Macy Gray | |
---|---|
Macy Gray ni 2008 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Natalie Renee McIntyre |
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kẹ̀sán 1967 (1967-09-06) (ọmọ ọdún 56) Canton, Ohio, United States |
Irú orin | R&B, soul, neo soul, hip hop |
Occupation(s) | Singer-songwriter, record producer, actress |
Years active | 1990–present |
Labels | Atlantic (1994-1996) Epic (1998-2004) will.i.am / Geffen (2006-2008) Concord (2009-2011) 429 (2011-) |
Associated acts | Bobby Brown, Natalie Cole, Velvet Revolver, Pharoahe Monch, The Black Eyed Peas |
Website | macygray.com |
Close