![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/1/17/Loquat-0.jpg/640px-Loquat-0.jpg&w=640&q=50)
Loquat
From Wikipedia, the free encyclopedia
Taxonomy not available for Eriobotrya; please create it automated assistant
Loquat | |
---|---|
![]() | |
Loquat leaves and fruits | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ] | |
Irú: | Template:Taxonomy/EriobotryaE. japonica |
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Template:Taxonomy/EriobotryaEriobotrya japonica (Thunb.) Lindl. | |
Synonyms[1] | |
|
loquat (Eriobotrya japonica),tí à ń pè ní biwa ní Japan, jẹ́ igi èso kékeré tàbí ńlá tí à ń gbín nítorí èso-ọsàn rẹ̀ fún orọ̀-ajé àti fún ewé e rẹ̀, èyí tí a fi ń ki àgbo. Bákan náà, a lè gbìn-ín fún ẹwà a rẹ̀. called biwa in Japan.
Loquat jẹ́ ìyekàn Rosaceae ó sì jẹ́ ìjímìjí àwọn apá ìlú òkè tó tutù south-central China.[2][3] Ní Japan, igi loquat ri jẹ́ ohun ọ̀gbìn fún bíi ẹgbẹ̀rún ọdún. Ó ti di ohun tí à ń gbìn káàkiri àwọn orílẹ̀-èdè tó gbóná fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ káàkiri àgbáye.[4]
Eriobotrya japonica ni a kọkọ rò pé ó tan pẹ̀lú genus Mespilus a sì tún máa ń ṣì í fún Japanese medlar, eléyìí tí ó jẹ́ orúkọ tí o ń jẹ́ ní àwọn èdè ìlú mìíràn ní Europe, bíi níspero japonés ní Spanish tàbí níspero japonés nespolo giapponese[5] àti Chinese plum.[6]