From Wikipedia, the free encyclopedia
Laura Chinchilla Miranda (ojoibi 28 March 1959) je oloselu ara Kosta Rika ati obinrin akoko Aare ile Kosta Rika. Ohun ni ikan ninu awon Igbakeji Aare si Óscar Arias Sánchez ati Alakoso Idajo ijoba re.[1] Ohun aduroibo fun egbe PLN fun idiboyan Aare ninu ibiboyan gbogbogbo odun 2010 nibi to ti bori pelu 46.76% awon ibo didi.[2] O je obinrin kefa ti yio je didiboyan bi Aare ni orile-ede Amerika Latini kan.[3] She was sworn as president of Costa Rica on May 8, 2010.[4]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Laura Chinchilla | |
---|---|
Aare ile Kosta Rika | |
In office 8 Osu Karun 2010 – 8 Osu Karun 2014 | |
Vice President | Àkọ́kọ́: Alfio Piva Ìkejì: Luis Liberman |
Asíwájú | Óscar Arias |
Arọ́pò | Luis Guillermo Solís |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kẹta 1959 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | National Liberation Party |
Alma mater | University of Costa Rica Georgetown University |
{{{blank1}}} | José María Rico |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.