Kenya
From Wikipedia, the free encyclopedia
Kẹ́nyà tàbí Orile-ede Olominira ile Kẹ́nyà je orile-ede ni Ìlaòrùn Áfríkà. O dubule si eba Okun India, ni agedemeji aye, Kẹ́nyà ni bode mo Ethiópíà (ariwa), Sòmálíà (ariwailaorun), Tànsáníà (guusu), Ùgándà ati Lake Victoria (iwoorun), ati Orile ede Gúúsù Sudan (ariwaiwoorun). Oluilu re ni Nairobi. Awon onibugbe ibe ti po to 38 legbegberun.
Quick Facts Orile-ede Olominira ile Kẹ́nyàRepublic of Kenya Jamhuri ya Kenya (Swahili), Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...
Orile-ede Olominira ile Kẹ́nyà Republic of Kenya Jamhuri ya Kenya (Swahili)
| |
---|---|
Motto: "Harambee" (Swahili) "Let us all pull together" | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Nairobi 1°16′S 36°48′E |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | |
National language | Swahili[1] |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2019[2]) |
|
Ẹ̀sìn (2019[2]) | Àdàkọ:Ublist |
Orúkọ aráàlú | Kenyan |
Ìjọba | Unitary presidential constitutional republic |
• Ààrẹ | Uhuru Kenyatta |
• Ìgbákejì Ààrẹ | William Ruto |
• Speaker of the Senate | Kenneth Lusaka |
• Speaker of the National Assembly | Justin Muturi |
• Chief Justice | David Maraga |
• Attorney General | Paul Kihara Kariuki |
Aṣòfin | Parliament |
• Ilé Aṣòfin Àgbà | Senate |
• Ilé Aṣòfin Kéreré | National Assembly |
Independence | |
• from the United Kingdom | 12 December 1963 |
• Republic declared | 12 December 1964 |
Ìtóbi | |
• Total | 580,367 km2 (224,081 sq mi)[3][4] (48th) |
• Omi (%) | 2.3 |
Alábùgbé | |
• 2019 census | 47,564,296[5] (29th) |
• Ìdìmọ́ra | 78/km2 (202.0/sq mi) (124th) |
GDP (PPP) | 2020 estimate |
• Total | $206.532 billion[6] |
• Per capita | $4,071[7] |
GDP (nominal) | 2020 estimate |
• Total | $109.116 billion[7] |
• Per capita | $2,151[7] |
Gini (2014) | 42.5[8] medium · 48th |
HDI (2018) | ▼ 0.579[9] medium · 147th |
Owóníná | Kenyan shilling (KSH) |
Ibi àkókò | UTC+3 (EAT) |
Irú ọjọ́ọdún | dd/mm/yy (AD) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | left |
Àmì tẹlifóònù | +254 |
Internet TLD | .ke |
[10] According to the CIA, estimates for this country explicitly take into account the effects of mortality because of AIDS; this can result in lower life expectancy, higher infant mortality and death rates, lower population and growth rates, and changes in the distribution of population by age and sex, than would otherwise be expected. |
Close