Kafayat Oluwatoyin Shafau (tí a bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 1980) tí òpòlopò ènìyàn mọ̀ sí Kaffy,[3] jé oníjó àti olùkọ́ni nípa ijójíjó. Oun tún ni ọ̀lùdásílẹ̀ ilé-isé ijó Imagneto. Ó gba àmì ẹ̀yẹ Guinness World record fún "Longest Dance party" ní Nokia Silver bird Danceathon ti ọdun 2007.[4]

Quick Facts Kaffy, Ọjọ́ìbí ...
Kaffy
Thumb
Kaffy ní ọdun 2013
Ọjọ́ìbíKafayat Oluwatoyin Shafau[1][2]
30 Oṣù Kẹfà 1980 (1980-06-30) (ọmọ ọdún 43)
Lagos, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaYaba College of Technology
Olabisi Onabanjo University
Iṣẹ́Dancer
Choreographer
Fitness coach
Ìgbà iṣẹ́2002 - present
OrganizationImagneto Dance Company
Àwọn ọmọ2
Close

Àárò ayé àti èkó rè

A bí Kaffy ni orílè-èdè Naijiria, o parí èkó primary re ní ilé-ìwé Chrisland, Opebi, ó sì ka ìwé Sekondiri ni ilé-ìwé Sekondiri ti Coker, Orile-Iganmu koto dipe o lo Yaba College of Technology, léyìn náà o lo yunifásitì Olabisi Onabanjo láti kékó gboye ninú Data Processing àti Computer Science,[5] bi o tile jé wipe ete rè ni láti di Aeronautic Engineer.

Isé rè

Isé Kaffy ninú ijo jijo bèrè nígbà ti arakurin kan ri ní National Stadium ti èkó tí ósì pè kowa jó lori ìtàgé.[6]

Ni odun 2006, Kaffy dari egbe ijo rè láti jó ijo fun wakati marundinlogota àti iseju ogoji(55 hours and 40 minutes), èyí mú ko gba ami èye Guinness Book of Record fun ijo tó pé jù, nkan èyí tí o so di gbajumo[7]

Ìdílé rè

Kaffy fé Joseph Ameh ní odun 2013 sùgbón wón ko ara won sílè léyìn odun mesan ní odun 2022. Àwon méjèjì bí omo méjì.[8]

Àwon ìtókasí

Wikiwand in your browser!

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.

Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.