Juice Wrld
From Wikipedia, the free encyclopedia
Jarad Anthony Higgins (tí wọ́n bí ní 2, 1998, tí ó sì kú ní December 8, 2019) tí orúkọ ìnágijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Juice Wrld, tí kíkọ sílẹ̀ rẹ̀ jẹ́ "Juice World ", jẹ́ ọmọọmọ olórin ilẹ̀ ìlú America, àti akọrin sílẹ̀. Ó jẹ́ aṣíwájú fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ "emo rap" àti "SoundCloud rap"
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Aláìsí ...
Juice Wrld | |
---|---|
Juice Wrld performing in July 2019 | |
Ọjọ́ìbí | Jarad Anthony Higgins (1998-12-02)Oṣù Kejìlá 2, 1998 Chicago, Illinois, U.S. |
Aláìsí | December 8, 2019(2019-12-08) (ọmọ ọdún 21) Oak Lawn, Illinois, U.S. |
Cause of death | Acute oxycodone and codeine intoxication |
Resting place | Beverly Cemetery, Blue Island, Illinois |
Ẹ̀kọ́ | Homewood-Flossmoor High School |
Iṣẹ́ |
|
Alábàálòpọ̀ |
|
Àwọn olùbátan | Young Dolph (second cousin) |
Website | juicewrld999.com |
Àdàkọ:Infobox musician |
Close
SoundCloud rap and genres, léyìí tí ó kó ọkàn àwọn ènìyàn ní àárín ọdún 2010. Orúkọ eré ìtàgé tí ó jẹ́ "ṣíṣe olórí ilé ayé" tí ó jẹ́ jáde láti inú eré sinimá àgbéléwò "crime thriller film Juice" (1992).