From Wikipedia, the free encyclopedia
Joy Olasunmibo Ogunmakin (tí á bí ni 14 September 1980), tí a mọ̀ sí Ayọ jẹ̀ ọ̀kọrin orílé èdè German, Ẹnití tí ó ma ń kọ orin silẹ àti òṣèré. Ó lo èdè Yorùbá láti tù orúkọ rẹ̀ tí ṣe JOY ni ede gẹ̀ẹ́sì sí èdè Yorùbá tíì ṣe Ayọ̀, èyí tí ó jẹ́ orúkọ àbísọ rẹ̀.
Ayọ | |
---|---|
Ayọ ní National Theatre tí ó wà ni Warsaw, ní 19 oṣù kọkànlá ọdún 2008 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Joy Olasunmibo Ogunmakin |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Ayọ, Ayo. |
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kẹ̀sán 1980 |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Cologne, West Germany |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments |
|
Years active | 2001–present |
Labels |
|
Website | ayomusic.com |
Debut album rẹ̀ tí ṣe Joyful, jáde ní ọdún 2006, èyí tí ó tí de Music recording sales certification Double-Platinun status ni orílé èdè France, Music recording sales certification Platinum ní Germany àti Poland, bákan náà Music recording sales certification Gold status ní Switzerland, Italy, àti Greece. Ilé iṣé orin Interscope ní ó ṣe alágbèkalè àwo orin rẹ̀ ní orílé èdè United States ni ojó kẹẹ̀dọgún oṣù kọkànlá ọdún 2007.
Wọ́n bí ni Frenchen èyí tí kò jìnà sí Cologne ní orílé èdè Germany, ọ sí ní ọmọ ọkùnrin tí orúkọ kọ rẹ̀ ń jẹ́ Nílé, tí ó bi ní ọdún 2005, ọ sí ní ọmọ Obìnrin tí í ṣe Billie-Eve ni oṣù keje odun,[1] Ó fún Olórinbkan tí orúkọ béè ni je Patrick Bart- Williams, èyí wọn tí wá ní ìpínyà.[2] ní oṣù kẹta odun 2017, ọ bí ọmọ kẹta tí orúkọ rẹ ní je Jimi-Julius èyí tí ó jẹ́ ọmọ kẹta.[3]
Kí ọdún 2002 tó parí, àti òun àti àwon mọ̀lẹ́bí rẹ̀ kó lọ sí Greenwich Village, apá kan ní Manhattan ni Newyork City.[4] Lọ́wọ́lọ́wọ́, ó ń gbé ní Brooklyn ni New York[5].
Lẹyìn èyí ni Ààre UNICEF tí orílé èdè Faransé, Jacques Hintzy, ṣe ipolongo ní ọjọ́ kẹrin Oṣù Kejì ọdún 2009 pé òun fí okọrin náà Jẹ Patron UNICEF tí yóò má jẹ́ kí ètò fún àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ lati ní ìmọ síwájú si ní àgbáyé.[6]
Ilé iṣé kàn ní orílé èdè Faransé Marin Karmitz MK2 ló ṣe àgbéjáde eré Ayọ̀ JOY, èyí tí ó jẹ́ èdè oníṣe tí ó wà fún aádọ́rún ìṣẹ́jú, tí ó lórí ìgbé ayé Ọ̀kọrin ní ọdún 2009. Raphael Duroy ní ọ jẹ Olùdarí Eré náà[7][8]
Albums
Singles
DVDs
|
EP
Contributions
Music videos
|
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.