![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/b/b1/Baker_Banana.jpg/640px-Baker_Banana.jpg&w=640&q=50)
Josephine Baker
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America / From Wikipedia, the free encyclopedia
Josephine Baker (June 3, 1906 – April 12, 1975) je onijo, akorin ati osere omo Amerika ara Fransi to je mimo kaakiri bi "Black Pearl," "Bronze Venus" ati "Creole Goddess". Oruko abiso re ni Freda Josephine McDonald ni St. Louis, Missouri, Josephine di ara Fransi ni 1937. O gbo ede Geesi ati ede Fransi daada.
Josephine Baker | |
---|---|
![]() Josephine Baker in her famous banana costume. | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Freda Josephine McDonald |
Ọjọ́ìbí | (1906-06-03)Oṣù Kẹfà 3, 1906 St. Louis, Missouri, U.S.[1][2] |
Aláìsí | April 12, 1975(1975-04-12) (ọmọ ọdún 68) Paris, France |
Irú orin | Cabaret, Music hall, French pop, French jazz |
Occupation(s) | Dancer, singer, actress, Civil Rights Activist, spy |
Instruments | Vocals |
Years active | 1921–1975 |
Labels | Columbia, Mercury, RCA Victor |
Baker ni omobinrin Afrika Amerika akoko to di osere pataki ninu filmu kan, Zouzou (1934) tabi to gbajumo kari aye gegebi onifaaji. Baker ko lati sere fun agbo eleyameya ni Amerika, be sini o tun kopa ninu Iwode awon Eto Araalu. Coretta Scott King fun ni ipo olori iwode yi ni odun 1968, leyin ifikupa Martin Luther King, Jr.. Baker, however, turned down the offer. She was also known for assisting the French Resistance during World War II,[3] and received the French military honor, the Croix de guerre and was made a Chevalier of the Légion d'honneur by General Charles de Gaulle.[4]