Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia
Jared Joseph Leto ( /ˈlɛtoʊ/ LEH-toh; tí a bí ní ọjọ́ kẹrindínlógbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1971) jẹ́ òṣèré àti olórin ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ nínú iṣẹ́ òṣèré tí ó ti ń ṣe fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún, àwọn àmì ẹyẹ bi Academy Award àti Golden Globe Award.[1] Pẹ̀lú pẹ̀lú, ó gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ orin kíkó gẹ́gẹ́ bi ara àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rock band Thirty Seconds to Mars.[2]
Jared Leto | |
---|---|
Leto ní San Diego Comic-Con ti ọdún 2016 | |
Ọjọ́ìbí | Jared Joseph Leto 26 Oṣù Kejìlá 1971 Bossier City, Louisiana, U.S. |
Orúkọ míràn |
|
Iléẹ̀kọ́ gíga | School of Visual Arts |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1992–present |
Works |
|
Alábàálòpọ̀ | Cameron Diaz (1999–2003) Valery Kaufman (2015–2022) |
Ẹbí | Shannon Leto (brother) |
Awards | Full list[lower-alpha 1] |
Website | thirtysecondstomars.com |
Musical career | |
Irú orin | Alternative rock |
Instruments |
|
Labels |
|
Lẹ́yìn ìgbà tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré nínú fíìmù My So-Called Life (1994), Leto ṣeré nínú How to Make an American Quilt (1995), ó sì gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ nínú fíìmù Prefontaine (1997). Ó tún ṣeré nínú àwọn fíìmù bi The Thin Red Line (1998), Fight Club (1999), Girl, Interrupted (1999) àti American Psycho (2000). Leto gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìyìn ipa rẹ̀ nínú Requiem for a Dream (2000). Lẹ́yìn èyí, ó bẹ̀rẹ̀ sí ń gbajúmọ́ isẹ́ orin kí ó tó padà sí isẹ́ òṣèré pẹ̀lú Panic Room (2002), Alexander (2004), Lord of War (2005), Chapter 27 (2007), àti Mr. Nobody (2009). Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Academy Award for Best Supporting Actor fún ipa rẹ̀ nínú Dallas Buyers Club (2013). Láàrin ọdún 2016 sí 2022, ó ṣeré nínú àwọn fíìmù bi Suicide Squad (2016), Blade Runner 2049 (2017), The Little Things (2021), House of Gucci (2021), àti Morbius (2022).
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.