Jamáíkà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Jamáíkà (pípè /dʒəˈmeɪkə/) je orile-ede erekusu ni Antilles Gbangba, to je 234 kilometres (145 miles) ni gigun ati bi 80 kilometres (50 miles) ni fife, ti isodipupo won je 11,100 km2. O budo sinu Okun Karibeani, bi 145 kilometres (90 miles) guusu Kuba, ati 190 kilometres (120 miles) iwoorun Hispaniola, erekusu to je ile fun awon orileabinibi-ileijoba Haiti ati Orile-ede Olominira Dominiki. Awon elede Arawak abinibi eya Taíno ti won gbe nibe pe oruko erekusu ohun ni Xaymaca, to tumosi "Ile Igi ati Omi", tabi "Ile Isun Omi".[4]
Jamáíkà | |
---|---|
Motto: "Out of Many, One People" | |
Orin ìyìn: "Jamaica, Land We Love" | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Kingston |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | English |
National language | Jamaican Patois |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 91.2% black, 6.2% mixed, 2.6% other[1] |
Orúkọ aráàlú | Jamaican |
Ìjọba | Parliamentary democracy and Constitutional monarchy |
• Obailu | Elizabeth II |
• Gomina-Agba | Patrick Allen |
• Alakoso Agba | Andrew Holness |
Ilominira | |
• latodo United Kingdom | 6 August 1962 |
Ìtóbi | |
• Total | 11,100 km2 (4,300 sq mi) (166th) |
• Omi (%) | 1.5 |
Alábùgbé | |
• July 2009 estimate | 2,825,928[1] (133rd) |
• Ìdìmọ́ra | 252/km2 (652.7/sq mi) (49th) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $23.797 billion[2] |
• Per capita | $8,777[2] |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $11.903 billion[2] |
• Per capita | $4,390[2] |
Gini (2000) | 37.9 medium |
HDI (2007) | ▼ 0.766[3] Error: Invalid HDI value · 100th |
Owóníná | Jamaican dollar (JMD) |
Ibi àkókò | UTC-5 |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | osi |
Àmì tẹlifóònù | +1-876 |
ISO 3166 code | JM |
Internet TLD | .jm |
Nigba kan bi ini Spein ti won si pe ibe ni Santiago, ni 1655 o di ibiamusin Ilegeesi, ati leyin eyi o di ti Britani, toruko re n je "Jamaica". Pelu awon eniyan ti won to egbegberun 2.8, o je orile-ede keta eledegeesi to ni awon eniyan pipojulo ni orile Amerika, leyin awon orile-ede Iparapo awon Ipinle ati Kanada. O wa ninu ile Ajoni pelu Queen Elizabeth II bi Olori Orile-ede. Kingston ni ilu titobijulo ati oluilu re.