From Wikipedia, the free encyclopedia
Gàbọ̀n ( /ɡəˈbɒn/; ìpè Faransé: [ɡabɔ̃]), lonibise bi Orile-ede Olominira ara Gabon (Faransé: République Gabonaise) je orile-ede ni iwoorun gbongan Afrika to ni bode mo Guinea Alagedemeji ni ariwaiwoorun, Cameroon ni ariwa, ati mo Orile-ede Olominira ile Kongo to lopo ni ilaorun ati guusu. Ikun-omi Guinea, apa Okun Atlantiki si iwoorun. Ile re tobi to 270,000 km² o si ni alabugbe to to 1,500,000. Oluilu ati ilu totobijulo re ni Libreville.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ará Gàbọ̀n Gabonese Republic République Gabonaise
| |
---|---|
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Libreville |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | French |
Vernacular languages | Fang, Myene |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2000) | Fang 28.6% Punu 10.2% Nzebi 8.9% French 6.7% Mpongwe 4.1% other Africans and Europeans 154,000 (including 10,700 French and 11,000 persons of dual nationality) |
Orúkọ aráàlú | Gabonese, Gabonaise |
Ìjọba | Orílẹ̀-èdè olómìnira oníààrẹ |
• Ààrẹ | Brice Oligui |
• Alákóso Àgbà | Raymond Ndong Sima |
Aṣòfin | Iléaṣòfin |
• Ilé Aṣòfin Àgbà | Ilé Alàgbà |
• Ilé Aṣòfin Kéreré | Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin |
Independence | |
• from France | August 17, 1960 |
Ìtóbi | |
• Total | 267,667 km2 (103,347 sq mi) (76th) |
• Omi (%) | 3.76% |
Alábùgbé | |
• 2009 estimate | 1,475,000[1] (150th) |
• Ìdìmọ́ra | 5.5/km2 (14.2/sq mi) (216th) |
GDP (PPP) | 2011 estimate |
• Total | $24.571 billion[2] |
• Per capita | $16,183[2] |
GDP (nominal) | 2011 estimate |
• Total | $16.176 billion[2] |
• Per capita | $10,653[2] |
HDI (2010) | ▲ 0.648[3] Error: Invalid HDI value · 93rd |
Owóníná | Central African CFA franc (XAF) |
Ibi àkókò | UTC+1 (WAT) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+1 (not observed) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | 241 |
Internet TLD | .ga |
Lati igba ilominira latowo Fransi ni August 17, 1960, awon aare meta loti joba ni Gabon. Ni arin ewadun 1990, Gabon bere sistemu egbe oloselu pupo ati isepo oloselu tuntun to fi aye gba igbese aladiboyan kedere to si satunse opo awon ise ijoba. Gabon ti je omo-egbe alaije tigba gbogbo ni Igbimo Abo UN fun igba 2010-2011.
Low Isupo alabugbe kekere lapapo mo opo awon ohun alumoni ati idawosi aladani okere ti so Gabon di ikan ninu awon orile-ede to jomitoro julo ni Afrika, pelu HDI to gajulo[4] ati GDP ti enikookan togajulo keta (PPP) (leyin Equatorial Guinea ati Botswana) ni agbegbe yi.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.