Guadalupe Victoria
From Wikipedia, the free encyclopedia
Guadalupe Victoria (29 September 1786- 21 March 1843),[1][2] tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ José Miguel Ramón Adaucto Fernández y Félix,[3] jẹ́ ológun ilẹ̀ Mexico nígbà kan rí, tó sì jagun fún Mexico lásìkò ìgbòmìnira wọn. Wọ́n fi jẹ ààrẹ ìlú Mexico àkọ́kọ́.[4]
Quick Facts The Most Excellent, 1st President of Mexico ...
The Most Excellent Guadalupe Victoria | |
---|---|
Portrait of Guadalupe Victoria by Carlos Paris | |
1st President of Mexico | |
In office 10 October 1824 – 31 March 1829 | |
Vice President | Nicolás Bravo (1824-1827), vacant (1827-1829)[lower-alpha 1] |
Asíwájú | Office established, Provisional Government (as governing body of Mexico) |
Arọ́pò | Vicente Guerrero |
President of the Supreme Executive Power | |
In office 1 July 1824 – 31 July 1824 | |
Asíwájú | Vicente Guerrero |
Arọ́pò | Nicolás Bravo |
Member of the Supreme Executive Power | |
In office 30 July 1834 – 10 October 1835 Serving with Miguel Domínguez Vicente Guerrero Nicolás Bravo Mariano Michelena Pedro Celestino Negrete | |
Governor of Puebla | |
In office 31 March 1834 – 13 December 1836 | |
Asíwájú | Patricio Furlong |
Arọ́pò | Cosme Furlong |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | José Miguel Ramón Adaucto Fernández y Félix 29 September 1786 Tamazula, Nueva Vizcaya, Viceroyalty of New Spain (now Durango, Mexico) |
Aláìsí | 21 March 1843 (aged 56) San Carlos Fortress, Perote, Veracruz, Mexico |
Resting place | Column of Independence |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Mexican New Spain (prior to 1821) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Independent party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | María Antonia Bretón (m. 1817) |
Relatives | Francisco Victoria (brother) |
Alma mater | San Ildefonso College |
Occupation | Lawyer Soldier (General) |
Signature |
Close