Godwin Obasi
From Wikipedia, the free encyclopedia
Godwin Olu Patrick Obasi FAAS ti abi ni (ọjọ́ kẹrinlelogun oṣù kèjìlá odun (1933 – ọjọ́ keta oṣù keta 2007) je onimọ nipa oju ojo ori ilẹ Naijiria ati akowe agba fun Ẹgbẹ Oju-ojo Agbaye (WMO) lati ọdun (1984 si 2003). Òun ni òṣìṣẹ́ akọ̀wé àkọ́kọ́ tí wọ́n dárúkọ rẹ̀ sí akọ̀wé àgbà àti ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà àkọ́kọ́ láti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olórí àjọ àjọ UN kan.