Glutamic acid
From Wikipedia, the free encyclopedia
Àdàkọ:Chembox KEGG
Quick Facts Identifiers, Properties ...
Glutamic acid | |
---|---|
Systematic name 2-Aminopentanedioic acid | |
Àwọn orúkọ mìíràn | 2-Aminoglutaric acid |
Identifiers | |
CAS number | 56-86-0 (L isomer) |
ChEBI | CHEBI:18237 |
SMILES | C(CC(=O)O)C(C(=O)O)N
|
InChI | 1/C5H9NO4/c6-3(5(9)10)1-2-4(7)8/h3H,1-2,6H2,(H,7,8)(H,9,10)
|
InChI key | WHUUTDBJXJRKMK-UHFFFAOYAD |
ChemSpider ID | 591 |
Properties | |
Fọ́múlà mólékùlù | C5H9NO4 |
Ìkójọ mọ́lù | 147.13 g mol−1 |
Appearance | white crystalline powder |
Density | 1.4601 (20 °C) |
Ojúàmì ìyọ́ |
199 °C, 472 K, 390 °F |
Solubility in water | 7.5 g/L (20 °C)[1] |
Solubility | 0.00035g/100g ethanol (25 °C)[2] |
Acidity (pKa) | 2.10, 4.07, 9.47 [3] |
Hazards | |
NFPA 704 | |
Àdàkọ:Cross(what is this?) (verify) Except where noted otherwise, data are given for materials in their standard state (at 25 °C, 100 kPa) | |
Infobox references |
Close
Glutamic acid (àgékúrú sí Glu tàbí E; tí ó ń kóòdù fún GAA or GAG) jẹ́ α-amino tí wọ́n ń lò lati ṣèdá àwọn protein nínú ara. Ó ní α-amino lẹ́gbẹ́ kan (èyí tí ó ní agbára −NH3+ lábẹ́ ààyé), àti α-carboxylic acid lẹ́gbẹ́ kan (èyí tí kò ní agbára −COO− lábẹ́ ààyé), àti carboxylic acid tí ó somọ́ lẹ̀gbẹ́, tí a sì kó wọn pọ́ sí àwọn tí kò lágbára lati túká sómi (ní pH ara), aliphatic amino acid. Kò ṣe pàtàkì lára ènìyàn nítorí ara lè ṣẹ̀dá rẹ̀. Ní ìmọ̀ àrùn ọpọlọ, carboxylate anion ti glutamate jẹ́ ohun tí ó máa ń fún neurotransmitter lágbára lati ṣisẹ́ ìtají àwọn ètò ọpọlọ.[4] Base tó ní hydrogen ion jẹ́ glutamate; tí radical rẹ̀ jẹ́ sì glutamyl.