Gemma ChanFrom Wikipedia, the free encyclopedia Gemma Chan jẹ́ òṣeré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ipa tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Crazy Rich Asians lọ́dún 2018 ló sọ ó di gbajúmọ̀ òṣèré ìlúmọ̀ọ́kà káàkiri gbogbo àgbáyé. [1] [2] [3] Gemma Chan
Gemma Chan jẹ́ òṣeré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ipa tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Crazy Rich Asians lọ́dún 2018 ló sọ ó di gbajúmọ̀ òṣèré ìlúmọ̀ọ́kà káàkiri gbogbo àgbáyé. [1] [2] [3] Gemma Chan