From Wikipedia, the free encyclopedia
Galileo Galilei (Àdàkọ:IPA-it; 15 February 1564[4] – 8 January 1642)[1][5] je ara Italia onimo fisiiki, mathematiiki, olutorawo, ati onimo oye to ko ipa pataki ninu Ijidide Sayensi. Die ninu awon aseyori re ni atunse si teliskopu ati awon akiyesi irawo to se, ati itileyin ise Copernicus. Won ti pe Galileo ni "baba itorawo oniakiyesi odeoni,"[6] "baba fisiiki odeoni,"[7] the "baba sayensi,"[7] ati "Baba Sayensi Odeoni."[8] Stephen Hawking so pe, "Galileo, ju elomiran, lo sise fun ibi sayensi odeoni."[9]
Galileo Galilei | |
---|---|
Portrait of Galileo Galilei by Giusto Sustermans | |
Ìbí | [1] Pisa,[1] Duchy of Florence, Italy | 15 Oṣù Kejì 1564
Aláìsí | 8 January 1642 ọdún 77)[1] Arcetri,[1] Grand Duchy of Tuscany, Italy | (ọmọ
Ibùgbé | Grand Duchy of Tuscany, Italy |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Italian |
Pápá | Astronomy, Physics and Mathematics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Pisa University of Padua |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Pisa |
Academic advisors | Ostilio Ricci[2] |
Notable students | Benedetto Castelli Mario Guiducci Vincenzio Viviani[3] |
Ó gbajúmọ̀ fún | Kinematics Dynamics Telescopic observational astronomy Heliocentrism |
Religious stance | Roman Catholic |
Signature | |
Notes His father was the musician Vincenzo Galilei. His mistress was Marina Gamba and Maria Celeste was one of Galileo's daughters. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.