![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/c/c5/Frederick_Douglass_%2528circa_1879%2529.jpg/640px-Frederick_Douglass_%2528circa_1879%2529.jpg&w=640&q=50)
Frederick Douglass
Olóṣèlú / From Wikipedia, the free encyclopedia
Frederick Douglass (oruko abiso Frederick Augustus Washington Bailey, February 1818[2] – February 20, 1895) je ara Amerika alatunse, alasodun, olukowe ati babaalu. Leyin igba to sakuro ni oko-eru, o di olori egbe irinkankan apokoerure, pelu oro kankan re[3] ati iwe alodi si oko-eru to ko. Ohun lo duro bi apere tolodi si ijiyan awon akonileru pe awon eru ko ni laakaye lati sise bi omo Amerika alominira.[4][5] Opo awon ara Ariwa na si tun nira lati gbagbo pe iru eni unla bayi ti je eru tele.[6]
Frederick Douglass | |
---|---|
![]() | |
Ọjọ́ìbí | February 1818[1] Talbot County, Maryland, United States |
Aláìsí | February 20, 1895 (aged about 77) Washington, D.C., United States |
Iṣẹ́ | Abolitionist, author, editor, diplomat |
Olólùfẹ́ | Anna Murray-Douglass (1838–1882) Helen Pitts (1884 to his death) |
Àwọn ọmọ | Charles Remond Douglass Rosetta Douglass Lewis Henry Douglass Frederick Douglass Jr. Annie Douglass (died at 10) |
Parent(s) | Harriet Bailey and perhaps Aaron Anthony |
Signature | |
![]() |
Douglass ko opo iwe igbesiayearaeni, nibi to ti ohun todun juwe irire ninu oko-eru ninu iwe igbesiayearaeni to ko ni 1845, Itan Igbesiaye Frederick Douglass, Eru ara Amerika, to kopa kikan nipa fifowokun ipokoerure. O tun ko iwe igbesiaraeni meji miran, eyi to gbeyin toko unje, Igbsiaye ati Igba Frederick Douglass, toje titejade ni 1881 to si dalori awon isele to waye nigba ati leyin Ogun Abele. Leyin Ogun Abele, Douglass ko kose ninu ijagudu Orile-ede Amerika lati di "ile olominira" looto. Douglass se itileyin eto idibo awon obinrin. Lai lowo unbe o di omo Afrika Amerika akoko to je didaloruko fun ipo Igbakeji Are Amerika bi elegbe ajodubo si Victoria Woodhull ti egbe oselu kekere Equal Rights Party. Douglass di opo ipo ijoba mu.
Douglass nigbagbo gidigidi ninu ijedogba gbogbo eniyan, boya o je adulawo, abo, Abinibi ara Amerika, tabi asesekowolu, o gbajumo pe o so pe, "Un o parapọ̀ mọ́ ẹni yìówù láti ṣe rere, unkò ní parapọ̀ ṣèbàjẹ́ pẹ̀lú ẹnìkankan." [7]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |