Remove ads
From Wikipedia, the free encyclopedia
Florin tí ó jẹyọ lati ìlú Florence (tàbí Firenze) ní Italy, wọ́n máa ń sábà pèé ní (fiorino d'oro) owó góólù tí wọ́n parun ní ọdún 1252. Wọ́n yá ìgúnrégé owó yìí ní àwọn orílẹ̀ èdè míràn àti pé wọ́n lo ọ̀rọ̀ florin, fún àpẹẹrẹ, ní ìbáṣepọ̀ sí Dutch guilder (àgékúrú sí FI) àti sí owó onírin àkọ́kọ́ tí Edward III of England tẹ̀ jade ní ọdún 1344 – tí iye tẹ̀ kúsí ṣílínì mẹ́fà.[1][2]
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.