From Wikipedia, the free encyclopedia
Filipínì tabi Àwọn Filipini (Àdàkọ:Lang-fil Àdàkọ:IPA-tl), fun onibise bi orile-ede Olominira ile awon Filipini (Àdàkọ:Lang-fil), je orile-ede kan ni Guusuilaorun Asia ni apaiwoorun Okun Pasifiki. Si ariwa re niwaju Luzon Strait ni Taiwan wa. Ni iwoorun niwaju Omi Okun Guusu Saina ni Vietnam wa. Omi Okun Sulu ni guusuiwoorun wa larin re ati erekusu Borneo, be si ni ni guusu ni Omi Okun Selebes pinniya kuro si awon erekusu Indonesia miran. O bode mo Omi Okun Filipini ni ilaorun. Oluilu re wa ni Manila.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Àwọn Filipínì Republic of the Philippines Republika ng Pilipinas
| ||
---|---|---|
Motto: Maka-Diyos, Maka-Tao, Makakalikasan, at Makabansa[1] ("For God, People, Nature, and Country") | ||
Orin ìyìn: Lupang Hinirang ("Chosen Land") | ||
Olùìlú | Manila | |
Ìlú tótóbijùlọ | Quezon City | |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Filipino (based on Tagalog) , English | |
Lílò regional languages | Bikol, Cebuano, Hiligaynon, Ilokano, Pampango, Pangasinense, Tagalog, Waray[2] | |
Optional languages | Spanish and Arabic[3] | |
National language | Filipino | |
Orúkọ aráàlú | Filipino/Filipina (feminine) | |
Ìjọba | Unitary presidential constitutional republic | |
• President | Rodrigo Duterte | |
• Vice President | Leni Robredo | |
• Senate President | Tito Sotto | |
• House Speaker | Lord Allan Velasco | |
• Supreme Court Chief Justice | Diosdado Peralta | |
Independence from Spain1 from United States | ||
• Established | April 27, 1565 | |
• Declared | June 12, 1898 | |
• Self-government | March 24, 1934 | |
• Recognized | July 4, 1946 | |
• Current constitution | February 2, 1987 | |
Ìtóbi | ||
• Land | 299,764 km2 (115,740 sq mi)[2] (72nd) | |
• Omi (%) | 0.61%[4] (inland waters) | |
Alábùgbé | ||
• 2009 estimate | 91,983,000[5] (12th) | |
• 2007 census | 88,574,614[6] | |
• Ìdìmọ́ra | 306.6/km2 (794.1/sq mi) (44th) | |
GDP (PPP) | 2009 estimate | |
• Total | $324.692 billion[7] | |
• Per capita | $3,520[7] | |
GDP (nominal) | 2009 estimate | |
• Total | $160.991 billion[7] | |
• Per capita | $1,745[7] | |
Gini (2006) | 45.8[4] Error: Invalid Gini value | |
HDI (2007) | ▲ 0.751[8] Error: Invalid HDI value · 105th | |
Owóníná | Peso (Filipino: piso) or PHP | |
Ibi àkókò | UTC+8 (PST) | |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+8 (not observed) | |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right[9] | |
Àmì tẹlifóònù | +63 | |
ISO 3166 code | PH | |
Internet TLD | .ph | |
|
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.