Erin
From Wikipedia, the free encyclopedia
Erin (tàbí àjànàkú) jẹ́ ẹranko afọ́mọlọ́mú orí ilẹ̀ títóbi tí a kà sí ìbátan méjì ti ẹbí Elephantidae (Ẹ̀dá-àjànàkú): Elephas àti Loxodonta. Irú erin mẹ́ta ló yè lóde òní: àjànàkú ọlọ́dàn Áfíríkà, àjànàkú onígbó Áfíríkà, àti àjànàkú Ásíà (tí a tún pè ní àjànàkú Íńdíà). Gbogbo irú erin yòókù ti kú run, àwọn kan kú run ní sànmánì olómidídì, ṣùgbọ́n, ó ṣeé ṣe pé àwọn aràrá erin abirun-lára kan yè títí dé nǹkan bíi 2,000 BCE.[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |