From Wikipedia, the free encyclopedia
Edna Adan Ismail (tí wọ́n bí ní born 8 September 1937) jẹ́ agbẹ̀bí, ajàfẹ́tọ̀ọ́mọnìyàn, ó sí tún jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ́ Mínísítà fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèrè, fún orílẹ̀-èdè Somalia[1] láti ọdún 2003 wọ 2006. Òun sì ni ààrẹ ẹgbẹ́ Victims of Torture.[2]
Ìlú Hargeisa ni wọ́n bí Ismail sí, ní 8 September 1937,[3] ó sì jẹ́ ọmọ oníṣègùn kan.[4] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ márùn-ún tí ìyá rè bí, àmọ́ méjì kú nínú wọn lásìkò ìbí wọn.[5][6]
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.