French DJ, olupilẹṣẹ, o nse ati iṣẹ ọna director From Wikipedia, the free encyclopedia
William Sami Étienne Grigahcine ( wọ́n bi ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù karùn-ún, ọdún 1986), tí wọ́n mọ orúkọ-ìtàgé rẹ̀ ní DJ Snake, jẹ́ Atọ́kùn rẹ́kọ̀dù Faransé. Ó àkọ́kọ́ rí ìfojúsí lára láàgbáyé ní ọdún 2013 láti ara wí pé ó ṣe ohun-èlò ajẹmórìn tí ó ní ṣe pẹ̀lú àgbègbè rẹ̀ tó dá ní tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ "Turn Down for What" (featuring Lil Jon).[1][2][3][4][5]
DJ Snake | |
---|---|
DJ Snake in 2020 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | William Sami Étienne Grigahcine |
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Kẹfà 1986 Parisi, Faransé |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Ermont, Faransé |
Irú orin |
|
Occupation(s) |
|
Years active | 2009– Di àsìkò yìí |
Labels |
|
Associated acts |
|
Website | djsnake.com |
Ó ṣe àkọ́kọ́ orin àgbáyé pẹ̀lú àwọn orin tó dá kọ "Bird Machine" and "Turn Down for What" ni ọdún 2013.[1][6][7] "Bird Machine" ṣe ìfọwọ́sọwọ́pọ̀ pẹ̀lú Akẹgbẹ́ olórin Faransé Alesia. Orin àdákọ náà jẹ́ gbígbà lọ́wọ́ Mad Decent, rẹ́kọ̀dù lébẹ́lì tí ó wà ní Los Angeles olówó rẹ̀ jẹ́ Diplo.
Wọ́n kéde DJ Snake láti má ṣíṣe lórí ìfọwọ́sọwọ́pọ̀ pẹ̀lú Diplo, tí wọ́n fẹ́ gbé orin náà jáde ọdún 2014; orin náà padà jáde mí ọdún 2015 released in 2015 as the single "Lean On" tó ṣe ìfọwọ́sọwọ́pọ̀ pẹ̀lú MØ àti Diplo's Major Lazer.[8][9][10] Ní ọjọ́ kọgbọ̀n oṣù kẹ́rin ọdún 2014, DJ Snake bọ́ sí ipò "Òṣèré tó gba wíwò" láti ọwọ́ FoxWeekly.[11] Òun àti Dillon Francis gba ìkéde gẹ́gẹ́ bí àwọn Òṣèré méjì tí wọ́n jẹ́ igi lọ́gbà ẹ̀yìn fún ara wọn fún sọ́mà Mothership Tour ni ọdún 2014 pẹ̀lú Skrillex.[12] Ní oṣù kẹ́ta ọdún 2018, Billboard Sọ orúkọ DJ Snake ní Òṣèré kẹsàn-án ní òdìnwọ̀ ọdún 2018 fún àwọn Akọrin-óníjó tí wọ́n pẹ̀ ní Billboard Dance 100.[13][14]
|url-status=
ignored (help)|url-status=
ignored (help)|url-status=
ignored (help)|url-status=
ignored (help)|url-status=
ignored (help)|url-status=
ignored (help)Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.