Dinara Safina
From Wikipedia, the free encyclopedia
Dinara Mikhailovna Safina (Rọ́síà: Динара Михайловна Сафина, Àdàkọ:Lang-tt), ojoibi April 27, 1986 ni Moscow, je agba tenis ara Rosia lati eya Tatari. Safina de ifunnipo No. 1 Lagbaye bi enikan.
Quick Facts Orílẹ̀-èdè, Ibùgbé ...
Orílẹ̀-èdè | Rọ́síà |
---|---|
Ibùgbé | Monte Carlo, Monaco |
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kẹrin 1986 (1986-04-27) (ọmọ ọdún 38) Moscow, Soviet Union |
Ìga | 1.82 m (5 ft 11 |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | 2000 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (two-handed backhand) |
Ẹ̀bùn owó | US10,585,640 |
Iye ìdíje | 360–173 (67.54%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 12 WTA, 4 ITF |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 1 (April 20, 2009) |
Open Austrálíà | F (2009) |
Open Fránsì | F (2008, 2009) |
Wimbledon | SF (2009) |
Open Amẹ́ríkà | SF (2008) |
Ìdíje WTA | RR (2008, 2009) |
Ìdíje Òlímpíkì | Silver medal (2008) |
Iye ìdíje | 181–91 |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 9 WTA, 3 ITF |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 8 (May 12, 2008) |
Open Austrálíà | QF (2004, 2005) |
Open Fránsì | 3R (2006, 2007, 2008) |
Wimbledon | 3R (2005, 2008) |
Open Amẹ́ríkà | W (2007) |
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn | |
Ìdíje Òlímpíkì | QF (2008) |
Last updated on: October 10, 2011. |
Close
Safina gba ipo keji ninu awon idije Grand Slam enikan ni 2008 French Open, 2009 Australian Open, ati 2009 French Open, nibi to ti kuna lowo Ana Ivanovic, Serena Williams, ati Svetlana Kuznetsova, ni telentele.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |