Ìpínlẹ̀ Delta
Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà / From Wikipedia, the free encyclopedia
Ipinle Delta je ipinle kan nini awon Ipinle ni orile-ede Naijiria. Ìpínlè Delta wà ní apa Guusu Nàìjíríà. Adá Ìpínlè Delta kalè ní ojo ketadinlogbon, osu kejo, odun 1991(27, August 1991) ní abe isejoba Gen. Ibrahim Babangida [1]. Olú-ìlú Ìpínlè Delta ní Asaba bí otile jepe ìlú Warri ìkan aje/oja kale sí jù. Àwon èyà tí opoju ní Ìpinlè Delta ni Igbo, Urhobo, Isoko, Ijaw, Itsekiri [2]. Ìpinlè Delta ní Ìjoba Agbegbe Ibile marundinlogbon(25) [3]Arakunrin Emmanuel Uduaaghan ti fi igba je gomina ipinle delta ri labe asia egbe oselu PDP. .Oruko gomina ipinle delta lowolowo bayii ni arakunrin Ifeanyi Okowa
More information Location, Statistics ...
Ìpínlẹ̀ Delta State nickname: The Big Heart | ||
Location | ||
---|---|---|
Statistics | ||
Governor (List) |
Emmanuel Uduaghan (PDP) | |
Date Created | 27 August 1991 | |
Capital | Asaba | |
Area | 17,698 km² Ranked 23rd | |
Population 1991 Census 2005 estimate |
Ranked 9th 2,570,181 4,710,214 | |
ISO 3166-2 | NG-DE |
Close