Dayo Oyewusi
From Wikipedia, the free encyclopedia
Dayo Oyewusi (tí wọ́n bí ní ọdún1966) jẹ́ abábọ́ọ̀lù badimíítìnì(badminton) Nàìjíríà .[1] Ó díje ní ọdún 1994 Commonwealth Games ní Victoria, Canada.[2] Ó gbé ipò kìíní ní ọdún 1991 ní ìdíje tí wọ́n ṣe ní Kenya fún àwọn obìnrin méjì papọ̀ lẹ́ẹ̀kan náà bíi ni kan tí ẹni Kejì rẹ̀ jẹ́ Obiageli Olorunsola.