D. O. Fagunwa
From Wikipedia, the free encyclopedia
Olóyè Daniel Oròwọlé Ọlórunfẹ́mi Fágúnwà MBE (1903 – 7 December 1963), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí D. O. Fágúnwà, Ó jẹ́ ògúná gbòngbò tí dá ìtàn àròsọ ní èdè Yorùbá sílẹ̀, ati olùkọ́ èdè Yorùbá nígbà ayé rẹ̀..[1]
Quick Facts Chief Daniel Ọlọ́runfẹ́mi Fágúnwà, Ọjọ́ ìbí ...
Chief Daniel Ọlọ́runfẹ́mi Fágúnwà | |
---|---|
Ọjọ́ ìbí | Daniel Oròwọlé Fágúnwà Àdàkọ:Birth year Oke-Igbo, Nigeria |
Ọjọ́ aláìsí | December 7, 1963(1963-12-07) (ọmọ ọdún 59–60) Bida, Nigeria |
Resting place | Oke-Igbo, Nigeria |
Iṣẹ́ | Olùkọ́ èdè Yorùbá ati ònkọ̀wé ìtàn àròsọ |
Èdè | Yorùbá |
Ìgbà | 1930–1963 |
Genre | Ìtàn Àròsọ (prose) |
Notable works | Ògbójú Ọdẹ nínú Igbó Irúnmọlẹ̀ ní ọdún 1938; Igbó Olódùmarè in 1949; Ìrèké Oníbùdó ọdún 1949; Ìrìnkérindò nínú Igbó Elégbèje ọdún 1954 Àdìtú Olódùmarè ọdún 1961 |
Spouse | Chief Elizabeth Adébánkẹ Fágúnwà (1932–2018) |
Close