Cherimoya
From Wikipedia, the free encyclopedia
Taxonomy not available for Annona; please create it automated assistant
Àdàkọ:Speciesbox/hybrid name | |
---|---|
Branch with leaves and fruit | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ] | |
Irú: | Template:Taxonomy/AnnonaA. cherimola |
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Template:Taxonomy/AnnonaAnnona cherimola Mill. | |
Current range of native and naturalized A. cherimola | |
Synonyms[1] | |
Annona pubescens Salisb. |
Cherimoya (Annona cherimola), ti a tun sipeli sí chirimoya ni a tun pe ni chirimuya lati owo awon eniyan Inca bákan naa, o je eya eso ti o nso eso jije ninu ẹyà Annona, lati ìdílè Annonaceae, ti o sunmọ sweetsop ati soursop. A gbagbọ wipe ohun ọgbin yìí se wa lati Ecuador ati Peru,[3] pẹlu igbin re ni Andes ati
Central America,[3][4][5] lotito aroso kàn so wipe Central America je orísun sugbon pupo ninu awon ebi ohun ọgbin yii po ni àdúgbò yìí.[5][6]
A máan gbin Cherimoya ni tropical ati subtropical region ni gbogbo kakiri àgbáye pẹlu Central America, northern South America, Southern California, South Asia, Australia, Mediterranean region, ati North Africa.[3][7] Akowe ile Amerika kàn ti a n pe ni Mark Twain pe cherimoya ni eso ti o dun julo.[8] Creamy texture eso yìí ni o je ki a ma pe ni kustardi apple.