From Wikipedia, the free encyclopedia
Charles Nohuoma Rotimi (tí wọ́n bí ní ọdún 1957) jẹ́ olùdarí àgbà ní National Institutes of Health (NIH) Ó ṣe ìdásílẹ̀ African Society of Human Genetics ní ọdún 2003. Rotimi kó ipa ribiribi nínú ìṣẹ̀dá Human Heredity and Health in Africa (H3Africa) pẹ̀lú ìrànwọ́ NIH àti Wellcome Trust. Wọ́n yàn án sínú ẹgbẹ́ National Academy of Medicine ní ọdún 2018.[1][2]
Charles Rotimi | |
---|---|
Rotimi interviewed by the NHGRI Oral History Collection in 2017 | |
Ìbí | Charles Nohuoma Rotimi 1957 (ọmọ ọdún 66–67) Benin City |
Ilé-ẹ̀kọ́ | Howard University Loma Linda University Loyola University Chicago NIH |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Benin (BS) University of Mississippi (MS) University of Alabama at Birmingham (MPH) University of Alabama at Birmingham (PhD) |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Elected to the National Academy of Medicine (2018) |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.