Bùrúndì (pipe /bəˈɹʊndɨ/), lonibise bi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bùrúndì (Kirundi: Republika y'u Burundi, [buˈɾundi]; Faransé: République du Burundi, [byˈʁyndi]), je orile-ede ademolesarin ni agbegbe awon Adagun Ninla ni Apailaorun Afrika to ni bode mo Rwanda ni ariwa, Tanzania ni ilaorun ati guusu, ati Orile-ede Olominira Oloselu ile Kongo ni iwoorun. Oluilu re ni Bujumbura. Botilejepe orile-ede na je ademolesarin, opo bode re ni apa guusuiwoorun wa niwaju Adagun Tanganyika.

Quick Facts Olùìlú, Ìlú tótóbijùlọ ...
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bùrúndì
Republic of Burundi  (English)

Republika y'u Burundi  (Kirundi)
République du Burundi  (Faransé)
Motto: "Ubumwe, Ibikorwa, Iterambere"  (Kirundi)
"Unité, Travail, Progrès"  (Faransé)
"Ọ̀kan, Iṣẹ́, Ìrewájú"
"Unity, Work, Progress" 1
Orin ìyìn: Burundi bwacu
(Our Burundi)
Thumb
Ibùdó ilẹ̀  Bùrúndì  (dark blue)

 Africa  (light blue & dark grey)
 in the African Union  (light blue)   [Legend]

OlùìlúBujumbura
Ìlú tótóbijùlọolúìlú
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaKirundi
Faransé
Àwọn èdè ìbílẹ̀Kirundi, Swahili
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
Hutu 85%
Tutsi 14%
Twa 1%
Orúkọ aráàlúará Bùrúndì
ÌjọbaOrílẹ̀-èdè olómìnira
 Ààrẹ
Évariste Ndayishimiye
 Igbákejì Ààrẹ 1k
Prosper Bazombanza
 Igbákejì Ààrẹ 2k
Gervais Rufyikiri
AṣòfinIléaṣòfin
 Ilé Aṣòfin Àgbà
Ilé Alàgbà
 Ilé Aṣòfin Kéreré
Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin
Ìlómìnira
 látọwọ́ Ibi-ilẹ̀ Ìdìmú UNBẹ́ljíọ́m sàmójútó
July 1, 1962 (UN Trust Territory) and July 1, 1966 (Independence of the Republic)
Ìtóbi
 Total
27,834 km2 (10,747 sq mi) (145th)
 Omi (%)
7.8
Alábùgbé
 2012 estimate
8,749,000[1] (89th)
 2008 census
8,053,574[2]
 Ìdìmọ́ra
314.3/km2 (814.0/sq mi) (45th)
GDP (PPP)2011 estimate
 Total
$5.184 billion[3]
 Per capita
$614[3]
GDP (nominal)2011 estimate
 Total
$2.356 billion[3]
 Per capita
$279[3]
Gini (1998)42.4[4]
Error: Invalid Gini value
HDI (2010) 0.282
Error: Invalid HDI value · 166th
OwónínáBurundi franc (FBu) (BIF)
Ibi àkókòUTC+2 (CAT)
 Ìgbà oru (DST)
UTC+2 (not observed)
Ojúọ̀nà ọkọ́ọ̀tún
Àmì tẹlifóònù257
ISO 3166 codeBI
Internet TLD.bi
  1. Before 1966, "Ganza Sabwa".
  2. Estimate is based on regression; other PPP figures are extrapolated from the latest International Comparison Program for benchmark estimates.
Close

Awon Twa, Tutsi, ati Hutu ni won ti ungbe ni Burundi latigba ti orile-ede na ti je didasile ni orundun marun seyin. Burundi je jijoba lelori bi ileoba latowo awon Tutsi fun ogorun meji odun. Sugbon latibere orundun ogun Jemani ati Belgium gba ori ibe won si so ibe di ileamusin to ruko re unje Ruanda-Urundi.

Cobalt ati baba ni meji ninu awon ohun alumoni ti Burundi ni. Bakanna Burundi unta kofi ati suga.

Àwọn ìpínlẹ̀ ìjọba

Burundi jẹ́ pípín sí ìgbèríko 18,[5] 117 communes,[6] and 2,638 collines (hills).[7] Provincial governments are structured upon these boundaries. In 2000, the province encompassing Bujumbura was separated into two provinces, Bujumbura Rural and Bujumbura Mairie.[8] The newest province, Rumonge, was created on 26 March 2015 from portions of Bujumbura Rural and Bururi.[9]

More information Ìgbèríko, Olúìlú ...
Close





Itokasi

Wikiwand in your browser!

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.

Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.