From Wikipedia, the free encyclopedia
Brandon James Routh ( /ˈraʊθ/; tí a bí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù Kẹ̀wá ọdún 1979)[1] jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó ṣeré Superman nínú fíìmù 2006 film Superman Returns, èyí tí ó mú kí ó gbajúmọ̀ káàkiri orílẹ̀ èdè. Ní ọdún 2011, ó ṣeré nínú fíìmù Dylan Dog: Dead of Night. Ó tún kó ipa Daniel Shaw nínú fíìmù NBC tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Chuck. Ara àwọn eré míràn tí Routh ti kópa ni Zack and Miri Make a Porno àti Scott Pilgrim vs. the World.
Ní ọdún 2014, ó kó ipa Ray Palmer / The Atom nínú eré Arrow. Ó tún kó ipa kan náà nínú Arrowverse shared universe: The Flash àti Legends of Tomorrow.
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.