![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/b/b5/Black_Panther_convention2.jpg/640px-Black_Panther_convention2.jpg&w=640&q=50)
Black Panther Party
From Wikipedia, the free encyclopedia
Black Panther Party (ti a mo si Black Panther Party fún ìdáàbòbò fún ara-ẹni ni igba ti won koko da sile) je egbe oselu fun idagbasoke ati ilosiwaju awon alawo dudu ni orile-ede Amerika larin odun 1960 titi de gbogbo odun 1970.
![Thumb image](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/b/b5/Black_Panther_convention2.jpg/640px-Black_Panther_convention2.jpg)
Quick Facts Ìdásílẹ̀, Ìtúká ...
Black Panther Party | |
---|---|
Fáìlì:Bpp logo.PNG | |
Ìdásílẹ̀ | 1966 (1966) |
Ìtúká | c. 1976 |
Ọ̀rọ̀àbá | Marxism-Leninism, Maoism, internationalism, socialism, Communism |
Ipò olóṣèlú | Far left |
Ìbáṣepọ̀ akáríayé | Algeria, Cuba, France |
Official colors | Black, Light Blue |
Close
Huey P. Newton ati Bobby Seale ni won da sile ni osu kewa odun 1966 ni Oakland ni Kalifọ́rníà.