Ìṣesósíálístì
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìṣesósíálístì (Socialism) je ero okowo ati oloselu to duro lori ini igboro tabi ikanna ati ibojuto alafowosowopo awon ona imuwaye ati ipin awon alumoni.[1][2][3]
Ninu sistemu okowo sosialisti, imuwaye je latowo ajose igboro awon olumuwaye lati muwaye taarata awon ohun iwulo (kuku awon ohun pasiparo), lona eto ipinu inawo, ipikakiri opo, ati lilo awon ona imuwaye. Isesosialisti je akojopo awon eto awujo ati okowo toduro lori sistemu isiro eyin eto owo, bi asiko ise, awon eyo okun tabi isiro iru ara.[4]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |