Billy Crudup
From Wikipedia, the free encyclopedia
William Gaither Crudup ( /ˈkruːdəp/; tí a bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù keje ọdún 1968)[1] jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orilẹ-èdè Amẹ́ríkà. Ipá rẹ̀ nínú fíìmù Jesus' Son (1999) jẹ́ kí wón yàn mọ́ àwọn tí ó tó sí Independent Spirit Award for Best Male Lead. Ó tún ṣeré nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré bi Almost Famous (2000), Big Fish (2003), Mission: Impossible III (2006), Watchmen (2009), Public Enemies (2009), The Stanford Prison Experiment (2015), Jackie (2016), àti Alien: Covenant (2017).
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Ẹ̀kọ́ ...
Close
Crudup gba àmì-ẹ̀yẹ Tony Award fún ipa rẹ̀ nínú fíìmù Tom Stoppard tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ The Coast of Utopia (2007). Ó tún ti ṣeré nínú àwọn eré bi Gypsy (2017), The Morning Show (2019), èyí tí ó mú kí ó gba àmì-ẹ̀yẹ Primetime Emmy Award àti Critics' Choice Television Award.