From Wikipedia, the free encyclopedia
Billie Catherine Lourd[1] (tí a bí ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gún oṣù keje ọdún 1992)[2] jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orilẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi l Chanel #3 nínú eré Fox tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Scream Queens (2015–2016) àti ipa rẹ̀ nínú FX tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ American Horror Story (2017–títí di ìsinsìnyí). Ó farahàn gẹ́gẹ́ bi Lieutenant Connix nínú àwọn eré Star Wars sequel (2015–2019). Lourd nìkan ni ọmọ òṣèrébìnrin Carrie Fisher.
Billie Lourd | |
---|---|
Lourd ní ọdún 2015 | |
Ọjọ́ìbí | Billie Catherine Lourd 17 Oṣù Keje 1992 Los Angeles, California, U.S. |
Ẹ̀kọ́ | Harvard-Westlake School |
Iléẹ̀kọ́ gíga | New York University (B.A.) |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2015–present |
Olólùfẹ́ | Austen Rydell (m. 2022) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Parents |
|
Àwọn olùbátan |
|
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.