From Wikipedia, the free encyclopedia
Bùrúndì (pipe /bəˈɹʊndɨ/), lonibise bi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bùrúndì (Kirundi: Republika y'u Burundi, [buˈɾundi]; Faransé: République du Burundi, [byˈʁyndi]), je orile-ede ademolesarin ni agbegbe awon Adagun Ninla ni Apailaorun Afrika to ni bode mo Rwanda ni ariwa, Tanzania ni ilaorun ati guusu, ati Orile-ede Olominira Oloselu ile Kongo ni iwoorun. Oluilu re ni Bujumbura. Botilejepe orile-ede na je ademolesarin, opo bode re ni apa guusuiwoorun wa niwaju Adagun Tanganyika.
Motto: "Ubumwe, Ibikorwa, Iterambere" (Kirundi) "Unité, Travail, Progrès" (Faransé) "Ọ̀kan, Iṣẹ́, Ìrewájú" "Unity, Work, Progress" 1 | |
Orin ìyìn: Burundi bwacu (Our Burundi) | |
Ibùdó ilẹ̀ Bùrúndì (dark blue) – ní Africa (light blue & dark grey) | |
Olùìlú | Bujumbura |
Ìlú tótóbijùlọ | olúìlú |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Kirundi Faransé |
Àwọn èdè ìbílẹ̀ | Kirundi, Swahili |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | Hutu 85% Tutsi 14% Twa 1% |
Orúkọ aráàlú | ará Bùrúndì |
Ìjọba | Orílẹ̀-èdè olómìnira |
• Ààrẹ | Évariste Ndayishimiye |
• Igbákejì Ààrẹ 1k | Prosper Bazombanza |
• Igbákejì Ààrẹ 2k | Gervais Rufyikiri |
Aṣòfin | Iléaṣòfin |
• Ilé Aṣòfin Àgbà | Ilé Alàgbà |
• Ilé Aṣòfin Kéreré | Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin |
Ìlómìnira | |
July 1, 1962 (UN Trust Territory) and July 1, 1966 (Independence of the Republic) | |
Ìtóbi | |
• Total | 27,834 km2 (10,747 sq mi) (145th) |
• Omi (%) | 7.8 |
Alábùgbé | |
• 2012 estimate | 8,749,000[1] (89th) |
• 2008 census | 8,053,574[2] |
• Ìdìmọ́ra | 314.3/km2 (814.0/sq mi) (45th) |
GDP (PPP) | 2011 estimate |
• Total | $5.184 billion[3] |
• Per capita | $614[3] |
GDP (nominal) | 2011 estimate |
• Total | $2.356 billion[3] |
• Per capita | $279[3] |
Gini (1998) | 42.4[4] Error: Invalid Gini value |
HDI (2010) | ▲ 0.282 Error: Invalid HDI value · 166th |
Owóníná | Burundi franc (FBu) (BIF) |
Ibi àkókò | UTC+2 (CAT) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+2 (not observed) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | ọ̀tún |
Àmì tẹlifóònù | 257 |
ISO 3166 code | BI |
Internet TLD | .bi |
|
Awon Twa, Tutsi, ati Hutu ni won ti ungbe ni Burundi latigba ti orile-ede na ti je didasile ni orundun marun seyin. Burundi je jijoba lelori bi ileoba latowo awon Tutsi fun ogorun meji odun. Sugbon latibere orundun ogun Jemani ati Belgium gba ori ibe won si so ibe di ileamusin to ruko re unje Ruanda-Urundi.
Cobalt ati baba ni meji ninu awon ohun alumoni ti Burundi ni. Bakanna Burundi unta kofi ati suga.
Burundi jẹ́ pípín sí ìgbèríko 18,[5] 117 communes,[6] and 2,638 collines (hills).[7] Provincial governments are structured upon these boundaries. In 2000, the province encompassing Bujumbura was separated into two provinces, Bujumbura Rural and Bujumbura Mairie.[8] The newest province, Rumonge, was created on 26 March 2015 from portions of Bujumbura Rural and Bururi.[9]
|
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.