Arsenio Hall
From Wikipedia, the free encyclopedia
Arsenio Hall (ojoibi February 12, 1956) je alawada, osere, atokun eto ibanisoro, olukowe ati olootu ara Amerika. O gbajumo nigba to se atokun eto The Arsenio Hall Show,[3] eto ale ibanisoro lori telifisan lati 1989 de 1994, ati lati 2013 de 2014.
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Iléẹ̀kọ́ gíga ...
Arsenio Hall | |
---|---|
Hall in July 2012 | |
Ọjọ́ìbí | 12 Oṣù Kejì 1956 (1956-02-12) (ọmọ ọdún 68) Cleveland, Ohio, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Kent State University |
Iṣẹ́ | Comedian, talk show host, actor, writer, producer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1984–present[1][2] |
Àwọn ọmọ | 1 |
Website | Official website |
Close