Apáàríwá Europe
From Wikipedia, the free encyclopedia
Apaariwa Europe je agbegbe ni iha àríwá orile Europe. Gege bi Ajo Isokan awon Orile-ede se so awon orile-ede wonyi ni won wa ni Apaariwa Europe:
- Dẹ́nmárkì
- Estóníà
- Fínlándì
- Íslándì
- Ireland
- Látfíà
- Lituéníà
- Nọ́rwèy
- Swídìn
- Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan
- Isle of Man
- Channel Islands: Guernsey and Jersey
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |