Óscar Arias
From Wikipedia, the free encyclopedia
Óscar Rafael de Jesús Arias Sánchez (ojoibi 13 September 1940) je oloselu ara orile-ede Kosta Rika to di Aare ile Kosta Rika lati odun 2006 de 2010. Teletele o tun je Aare lati 1986 de 1990 o si gba Ebun Nobel ni 1987 fun iyanju re lati mu opin ba awon ogun abele ti won nlowo nigbana ni opo awon orile-ede Aarin Amerika.
Quick Facts President of Costa Rica, Asíwájú ...
Óscar Arias | |
---|---|
President of Costa Rica | |
In office 8 Ọṣù Kàrún 2006 – 8 Ọṣù Kàrún 2010 | |
Asíwájú | Abel Pacheco |
Arọ́pò | Laura Chinchilla |
In office 8 Ọṣù Kàrún 1986 – 8 Ọṣù Kàrún 1990 | |
Asíwájú | Luis Alberto Monge |
Arọ́pò | Rafael Ángel Calderón Fournier |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Kẹ̀sán 1940 (1940-09-13) (ọmọ ọdún 83) Heredia, Costa Rica |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | National Liberation Party |
Alma mater | Boston University University of Costa Rica London School of Economics University of Essex |
Close