![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/4/4a/African_nations_order_of_independence_1950-1993.gif/640px-African_nations_order_of_independence_1950-1993.gif&w=640&q=50)
Òmìnira ilẹ̀ Áfríkà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Òmìnira ilẹ̀ Áfríkà jẹ́ ǹkan tí ó ṣẹlẹ̀ láàrin àwọn ọdún 1950s sí 1975 nígbà Cold War, tí ọ̀pọ̀lopọ̀ orílẹ̀ èdè sì gba òmìnira. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ló mú wàhálà àti àìsimin dání, díè nínú wọn ni Mau Mau rebellion ní British Kenya, Algerian War ní French Algeria, Congo Crisis ní Belgian Congo, Angolan War of Independence ní Portuguese Angola, Zanzibar Revolution ní Sultanate of Zanzibar, àti Ogun Abele Nàìjíríà tí Biafra àti ìjọba Nàìjíríà jà.[1][2][3][4][5]
![Thumb image](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/4/4a/African_nations_order_of_independence_1950-1993.gif/320px-African_nations_order_of_independence_1950-1993.gif)