Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìpínlẹ̀ Násáráwá je ikan ninu àwon Ipinle 36 ni orile-ede Naijiria. Oluilu re ni Lafia.
Ìpínlẹ̀ Násáráwá Nasarawa State | |
---|---|
Nickname(s): | |
Location of Nasarawa State in Nigeria | |
Country | Nigeria |
Date created | 1 October 1996 |
Capital | Lafia |
Government | |
• Governor[1] | Umar Tanko al-Makura (APC) |
• Representatives | List |
Area | |
• Total | 27,117 km2 (10,470 sq mi) |
Population (2005) | |
• Total | 2,040,097 |
• Density | 75/km2 (190/sq mi) |
GDP (PPP) | |
• Year | 2007 |
• Total | $3.02 billion[2] |
• Per capita | $1,588[2] |
Time zone | UTC+01 (WAT) |
ISO 3166 code | NG-NA |
Website | nasarawastate.org |
Ìpínlẹ̀ Nasarawa jẹ́ dídásílẹ̀ ní Ọjó kínní, osù kẹwàá, Ọdún 1996 nígbà ìsèjọba Abacha, tí wọ́n pín kúrò ní ìpínlẹ̀ Plateau odè oní.[3]
Awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Nasarawa jẹ́ mẹ́tàlá. (Afìhàn pẹ̀lú ònkà 2006 population[4]):
Awọn orísìrísí èdè tí ó wà ní ìpínlè Nasarawa jẹ́ mókàndínlógbọ̀n.
Awọn èdè na wa nínú tábìlì yi ní nítítò Ijọba ìbílẹ̀ ìpínlè Nasarawa:[5]
LGA | Languages |
---|---|
Akwanga | Mada;Duhwa; Eggon; Fulani; Gwandara; Hausa; Mama; Ninzo; Numana; Nungu |
Awe | Hausa; Fulani; Gwandara; Eggon; Goemai; Lijili; Tiv; Wapan |
Doma | Alago; Tiv; Agatu; Fulani; Hausa; |
keffi | Hausa; Fulani; :madaGadeEggon;Gbagyi; Gwandara; Koro Wachi |
Karu | Gbagyi; Gwandara; Gade |
Keana | Alago; Gwandara Tiv; Fulani |
Kokona | Gwandara;mada Fulani; Hausa; Eggon |
Lafia | Bare-Bari; Hausa; Fulani; Ake;mada: Alago; Agatu; Eggon; Goemai; Gwandara; Kofyar; Lijili; Tiv; Wapan |
Nasarawa | Hausa; Fulani; Agatu; Alago; Basa; Egbura; Eloyi; Gade; Gbagyi; Gwandara; Eggon; Tiv |
Nasarawa-Eggon | Eggon; Mada; Nungu; Fulani; Hausa |
Obi | Alago; Hausa; Fulani; Eggon; Tiv |
Toto | Egbura Agatu; Eggon; Gade; Fulani; Hausa |
Wamba | Alumu-Tesu;ninzo:mada;rindre Bu; Eggon; Hasha; Fulani; Kantana; Nungu; Toro |
Ní ìpínlè Nasarawa, orísìrísí ẹ̀yà marundinlogbon ló wà. Àwọn tí wọn ma n sọ jù nì Miligi (Koro), Alago, Mada, Gwandara, Kunari, Hausa Fulani, Gwari, Rindre, Afo, Eggon and Ebina[6]
Ìpínlẹ̀ Nasarawa ni awọn Ilé ẹ̀kọ́ bí:
Ìpínlè Nasarawa ní awọn ilé ẹ̀kọ́ alakobere àti girama bí the Federal Government Girls College, Kea.
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.