From Wikipedia, the free encyclopedia
Ede Wolof jẹ èdè tí à ń sọ ni atí bèbè Senegal Mílíọ̀nù méjì-àbọ̀ niye àwọn tó ń sọ. Awọn Olùbágbè wọn ni Mandika ati Fulaní. Awọn isẹ́ ọna wọn màa ń rewà tó sì ma ń ní àmìn àti àwòràn àwọn asáájú nínú ẹ̀sìn musulumi. Ìtan Wolof ti wà láti bí ẹgbẹ̀rún ọdún méjìlá tàbí métàlá sẹ́yìn. Ìtàn ẹbí alátẹnudẹ́nu wọn sọ pé ọ̀kan lára àwọn tó kọkọ tẹ̀dó síbí yìí jẹ́ awọn to wa láti orífun Fulbe. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìtàn Wolof ni a le rí nínú àwọn orin oríkì èyí ti a ma ń gbọ́ láti ẹnu àwọn ‘Griots’ àwọn akéwì. Mùsùlùmí ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọnm ará Wolof.
Wolof | |
---|---|
Sísọ ní | Sẹ̀nẹ̀gàl Mauritáníà |
Agbègbè | West Africa |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 3.2 million (mother tongue) 3.5 million (second language) [1] |
Èdè ìbátan | Niger-Kóngò
|
Lílò bíi oníbiṣẹ́ | |
Èdè oníbiṣẹ́ ní | Kòsí |
Àkóso lọ́wọ́ | CLAD (Centre de linguistique appliquée de Dakar) |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-1 | wo |
ISO 639-2 | wol |
ISO 639-3 | either: wol – Wolof wof – Gambian Wolof |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.