Sẹ̀nẹ̀gàl (Faransé: le Sénégal) tabi Orile-ede Olominira ile Senegal je orile-ede ni Iwoorun Afrika. Senegal ni Okun Atlantiki ni iwoorun, Mauritania ni ariwa, Mali ni ilaorun, ati Guinea ati Guinea-Bissau ni guusu. Sinu die lo ku ko yipo Gambia ka patapata si ariwa, ilaorun ati guusu, ibi to se ku nikan ni eti okun Atlanti Gambia[4] Ifesi ile Senegal fe to 197,000 km², be si ni o ni onibugbe bi 18 milionu.

Quick Facts Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàl République du Sénégal, Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàl
République du Sénégal
Motto: "Un Peuple, Un But, Une Foi"  (French)
"One People, One Goal, One Faith"
Location of Sẹ̀nẹ̀gàl
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Dakar
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaFrench
Lílò regional languagesWolof, Soninke, Seereer-Siin, Fula, Maninka, Diola,[1]
Orúkọ aráàlúSenegalese
ÌjọbaSemi-presidential republic
 President
Bassirou Diomaye Faye
 Prime Minister
Ousmane Sonko
Independence
 from France
4 April 1960
Ìtóbi
 Total
196,723 km2 (75,955 sq mi) (87th)
 Omi (%)
2.1
Alábùgbé
 2023 estimate
18,032,473[2] (61nd)
 Ìdìmọ́ra
92/km2 (238.3/sq mi)
GDP (PPP)2008 estimate
 Total
$21.773 billion[3]
 Per capita
$1,739[3]
GDP (nominal)2008 estimate
 Total
$13.350 billion[3]
 Per capita
$1,066[3]
Gini (1995)41.3
medium
HDI (2007)0.464
Error: Invalid HDI value · 166th
OwónínáCFA franc (XOF)
Ibi àkókòUTC
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù221
Internet TLD.sn
Close

Dakar ni oluilu re to wa lori Cap-Vert Peninsula ni eti Okun Atlantiki. Bi iye ida kan ninu meta awon ara Senegal ni won n gbe labe ila aini kakiriaye to je US$ 1.25 lojumo.[5]

Itokasi

Wikiwand in your browser!

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.

Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.